Chronological Bible
Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ (OYCB)
-
4004 sí 2347 ṣáájú ìbí Kristi
Àkókò 1 Láti Ìṣẹ̀dá sí Ìkún Omi
4004 sí 2347 ṣáájú ìbí Kristi- 4004 ṣáájú ìbí KristiApá 1: Ìṣẹ̀dá 4004 ṣáájú ìbí Kristi
- 4004 ṣáájú ìbí KristiApá 2: Ọjọ́ Ìsinmi àti Ìṣubú Ènìyàn 4004 ṣáájú ìbí Kristi
- 4003 ṣáájú ìbí KristiApá 3: Adamu àti Àwọn Àtọmọdọ́mọ Rẹ̀ Títí dé Ìkún Omi 4003 ṣáájú ìbí Kristi
- 3074 ṣáájú ìbí KristiApá 4: Ìtàn Ìran Àwọn Baba Ńlá 3074 ṣáájú ìbí Kristi
- 2468 ṣáájú ìbí KristiApá 5: Ayé Ní Kété Ṣáájú Ìkún Omi 2468 ṣáájú ìbí Kristi
- 2348 ṣáájú ìbí KristiApá 6: Ìkún Omi 2348 ṣáájú ìbí Kristi
- 2347 ṣáájú ìbí KristiApá 7: Májẹ̀mú Pẹ̀lú Noa 2347 ṣáájú ìbí Kristi
- 2347 ṣáájú ìbí KristiApá 8: Noa Sọ Ohun Tí Yóò Ṣẹlẹ̀ sí Àwọn Ọmọkùnrin Rẹ̀ Tẹ́lẹ̀ 2347 ṣáájú ìbí Kristi
-
2348 sí 1577 ṣáájú ìbí Kristi
Àkókò 2 Láti Ìfọ́n Káàkiri sí Ìjáde
2348 sí 1577 ṣáájú ìbí Kristi-
2348 sí 2234 ṣáájú ìbí KristiApá 1: A Da Àwọn Èdè Rú, A sì Fọ́ Aráyé Ká 2348 sí 2234 ṣáájú ìbí Kristi
- Ilé gogoro Babeli
- Àtòkọ àwọn orílẹ̀-èdè
- 2348 ṣáájú ìbí KristiÌtàn Ìran Ṣemu 2348 ṣáájú ìbí Kristi
-
2130 ṣáájú ìbí KristiApá 2: Ìgbésí Ayé Jobu 2130 ṣáájú ìbí Kristi
- Ìwà àti Ọ̀pọ̀lọpọ̀ Ohun Ìní Jobu
- Ìdánwò Àkọ́kọ́ Jobu
- Ìdánwò Kejì Jobu
- Àwọn Ọ̀rẹ́ Jobu Bẹ̀ Ẹ́ Wò, Wọ́n sì Gbọ́ Àwọn Ẹ̀dùn Ọkàn Rẹ̀
- Elifasi Sọ Pé Jobu Ń Jìyà Nítorí Àwọn Ẹ̀ṣẹ̀ Rẹ̀
- Jobu Dá Elifasi Lóhùn
- Bilidadi Tẹ̀ Síwájú nínú Àríyànjiyàn Náà
- Jobu Dá Bilidadi Lóhùn: Ìpọ́njú Kì Í Ṣe Ẹ̀rí Ìwà Búburú
- Sofari Fi Ọ̀rọ̀ Líle Rọ Jobu Láti Ronúpìwàdà
- Jobu Dá Gbogbo Àríyànjiyàn Náà Lóhùn
- Àríyànjiyàn Kejì Jobu Pẹ̀lú Àwọn Ọ̀rẹ́ Rẹ̀
- Jobu Kéde Àìlẹ́ṣẹ̀ Rẹ̀
- Bilidadi Dá Jobu Lóhùn
- Jobu Ráhùn Nípa Ìwà Ìkà Àwọn Ọ̀rẹ́ Rẹ̀
- Sofari Dá Jobu Lóhùn
- Jobu Dá Sofari Lóhùn
- Elifasi Bẹ̀rẹ̀ Àríyànjiyàn Kẹta
- Ìdáhùn Jobu nínú Àríyànjiyàn Kẹta
- Bilidadi Tún Tẹ̀ Síwájú nínú Àríyànjiyàn Náà
- Jobu Tún Fìdí Ìwà Títọ́ Rẹ̀ Múlẹ̀
- Elihu Sọ Pé Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run Ni Ìpọ́njú Ti Wá
- Ọlọ́run Farahàn Jobu àti Àwọn Ọ̀rẹ́ Rẹ̀
- Jobu Rẹ Ara Rẹ̀ Sílẹ̀
- Ọlọ́run Parí Ọ̀rọ̀ Rẹ̀ sí Jobu
- Jobu Tẹríba Pátápátá
- A Dá Aásìkí Jobu Padà
-
1996 sí 1821 ṣáájú ìbí KristiApá 3: Ìgbésí Ayé Abrahamu 1996 sí 1821 ṣáájú ìbí Kristi
- Ìpè Abramu àti Àkókò Rẹ̀ ní Ejibiti
- Abramu àti Lọti Pínyà
- 1920 ṣáájú ìbí KristiA Tún Ìlérí fún Abramu Ṣe 1920 ṣáájú ìbí Kristi
- 1912 ṣáájú ìbí KristiOgun Pẹ̀lú Àwọn Ọba Márùn-ún 1912 ṣáájú ìbí Kristi
- Melkisedeki Súre fún Abramu
- Májẹ̀mú Ọlọ́run Pẹ̀lú Abramu
- Ìbí Iṣmaeli
- 1897 ṣáájú ìbí KristiA Tún Májẹ̀mú Pẹ̀lú Abrahamu Ṣe 1897 ṣáájú ìbí Kristi
- A Fi Ìkọlà Lélẹ̀
- 1899 ṣáájú ìbí KristiA Ṣèlérí Ọmọkùnrin fún Abrahamu 1899 ṣáájú ìbí Kristi
- A Dá Sodomu Lẹ́bi, A sì Pa Á Run
- Lọti àti Àwọn Ọmọbìnrin Rẹ̀ Méjì
- 1897 ṣáájú ìbí KristiAbrahamu ní Gerari 1897 ṣáájú ìbí Kristi
- 1896 ṣáájú ìbí KristiÌbí Isaaki 1896 ṣáájú ìbí Kristi
- 1892 ṣáájú ìbí KristiA Rán Hagari àti Iṣmaeli Lọ 1892 ṣáájú ìbí Kristi
- Májẹ̀mú Abrahamu Pẹ̀lú Abimeleki
- 1871 ṣáájú ìbí KristiỌlọ́run Dán Abrahamu Wò 1871 ṣáájú ìbí Kristi
- 1859 ṣáájú ìbí KristiIkú àti Ìsìnkú Sara 1859 ṣáájú ìbí Kristi
- Ìdílé Rebeka
- 1856 ṣáájú ìbí KristiIsaaki Fẹ́ Rebeka 1856 ṣáájú ìbí Kristi
- Abrahamu Fẹ́ Ketura
- 1836 ṣáájú ìbí KristiÌbí Esau àti Jakọbu 1836 ṣáájú ìbí Kristi
- 1821 ṣáájú ìbí KristiIkú Abrahamu 1821 ṣáájú ìbí Kristi
-
1804 sí 1729 ṣáájú ìbí KristiApá 4: Láti Ikú Abrahamu sí Títà Josẹfu 1804 sí 1729 ṣáájú ìbí Kristi
- Esau Ta Ẹ̀tọ́ Àkọ́bí Rẹ̀
- 1773 ṣáájú ìbí KristiIkú Iṣmaeli 1773 ṣáájú ìbí Kristi
- Ìdílé Iṣmaeli
- 1760 ṣáájú ìbí KristiJakọbu Gba Ìbùkún Baba Rẹ̀ 1760 ṣáájú ìbí Kristi
- Jakọbu Rìnrìn Àjò sí Padani-Aramu
- 1752 ṣáájú ìbí KristiJakọbu Ń Gbé Pẹ̀lú Labani 1752 ṣáájú ìbí Kristi
- 1739 ṣáájú ìbí KristiJakọbu Fi Labani Sílẹ̀ 1739 ṣáájú ìbí Kristi
- 1738 ṣáájú ìbí KristiJakọbu Rìnrìn Àjò sí Sukkoti 1738 ṣáájú ìbí Kristi
- 1736 ṣáájú ìbí KristiÀwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ní Ṣalemu, tàbí Ṣekemu 1736 ṣáájú ìbí Kristi
- 1729 ṣáájú ìbí KristiJakọbu Sá Kúrò ní Ṣekemu, Ó sì Padà sọ́dọ̀ Baba Rẹ̀ 1729 ṣáájú ìbí Kristi
- Ìdílé Esau
-
1728 sí 1704 ṣáájú ìbí KristiApá 5: Josẹfu àti Ìdílé Rẹ̀ ní Ejibiti 1728 sí 1704 ṣáájú ìbí Kristi
- A Ta Josẹfu sí Ejibiti
- 1718 ṣáájú ìbí KristiÌdílé Juda 1718 ṣáájú ìbí Kristi
- A Fi Josẹfu Sẹ́wọ̀n
- 1717 ṣáájú ìbí KristiJosẹfu Tú Àlá Àwọn Ẹlẹ́wọ̀n Ẹlẹgbẹ́ Rẹ̀ 1717 ṣáájú ìbí Kristi
- Ikú Isaaki
- A Gbé Josẹfu sí Ipò Àṣẹ
- 1707 ṣáájú ìbí KristiÀwọn Arákùnrin Josẹfu Lọ sí Ejibiti fún Ọkà ní Ìgbà Àkọ́kọ́ 1707 ṣáájú ìbí Kristi
- 1706 ṣáájú ìbí KristiÀwọn Arákùnrin Josẹfu Padà, Jakọbu sì Tẹ̀lé Wọn 1706 ṣáájú ìbí Kristi
- 1704 ṣáájú ìbí KristiJosẹfu Ṣàkóso Ejibiti 1704 ṣáájú ìbí Kristi
-
1689 sí 1577 ṣáájú ìbí KristiApá 6: Ikú Jakọbu àti Àwọn Baba Ńlá 1689 sí 1577 ṣáájú ìbí Kristi
- Jakọbu Súre fún Àwọn Ọmọkùnrin Rẹ̀, Ó sì Kú
- Ìsìnkú Jakọbu àti Ikú Josẹfu
- 1577 ṣáájú ìbí KristiA Ni àwọn ará Israẹli Lára Lẹ́yìn Ikú Josẹfu 1577 ṣáájú ìbí Kristi
-
-
1571 sí 1451 ṣáájú ìbí Kristi
Àkókò 3 Láti Ìbí Mose sí Ikú Rẹ̀
1571 sí 1451 ṣáájú ìbí Kristi- 1571 ṣáájú ìbí KristiApá 1: Ìbí Mose àti Ìgbésí Ayé Rẹ̀ ní Ìbẹ̀rẹ̀ 1571 ṣáájú ìbí Kristi
- 1491 ṣáájú ìbí KristiApá 2: A Yan Mose fún Iṣẹ́ 1491 ṣáájú ìbí Kristi
- 1491 ṣáájú ìbí KristiApá 3: Láti Iṣẹ́ Mose sí Àwọn Ìyọnu Ejibiti 1491 ṣáájú ìbí Kristi
-
1491 ṣáájú ìbí KristiApá 4: Àwọn Ìyọnu Mẹ́jọ Àkọ́kọ́ 1491 ṣáájú ìbí Kristi
- 1491 ṣáájú ìbí KristiApá 5: A Dá ìrékọjá Sílẹ̀ 1491 ṣáájú ìbí Kristi
-
1491 ṣáájú ìbí KristiApá 6: Àwọn Ìyọnu Mẹ́wàá Parí 1491 ṣáájú ìbí Kristi
- 1491 ṣáájú ìbí KristiApá 7: Ìjáde 1491 ṣáájú ìbí Kristi
-
1491 sí 1451 ṣáájú ìbí KristiApá 8: Rírìn Káàkiri ní Aginjù 1491 sí 1451 ṣáájú ìbí Kristi
- Ìrìn Àjò Àkọ́kọ́: Láti Ramesesi sí Sukkoti
- A Tún Àṣẹ Láti Pa ìrékọjá Mọ́ Sọ
- Ìrìn Àjò Kejì: Láti Sukkoti sí Etamu
- Ìrìn Àjò Kẹta: Láti Etamu sí Pi-Hahirotu
- Ẹgbẹ́ Ọmọ Ogun Farao Ń Sún Mọ́lé
- Ìrìn Àjò Kẹrin: La Òkun Pupa Kọjá sí Mara
- Líla Òkun Pupa Kọjá
- Orin Mose ní Òkun Pupa
- Àwọn Ènìyàn Kùn ní Mara
- Ìrìn Àjò Karùn-ún: Láti Mara sí Elimu
- Ìrìn Àjò Kẹfà: Láti Elimu sí Ibùdó Lẹ́gbẹ̀ẹ́ Òkun Pupa
- Ìrìn Àjò Keje: Sí Aṣálẹ̀ Sini
- Àwọn Ènìyàn Kùn fún Búrẹ́dì
- Ìrìn Àjò Kẹjọ: Láti Aṣálẹ̀ Sini sí Dofka
- Ìrìn Àjò Kẹsàn-án: Láti Dofka sí Aluṣi
- Ìrìn Àjò Kẹwàá: Láti Aluṣi sí Refidimu
- Kíkùn fún Omi, àti Ogun Pẹ̀lú Amaleki
- Ìrìn Àjò Kọkànlá: Láti Refidimu sí Sinai
- Fífúnni ní Òfin
- A Kéde Òfin Ìwà
- Òfin Ìdájọ́
- Mose Gòkè Òkè Ńlá
- Òfin Àwọn Ààtò Ìsìn àti Àwòrán Ètò Àgọ́ Ìjọsìn
- A Ya Aaroni àti Àwọn Ọmọkùnrin Rẹ̀ Sọ́tọ̀
- Ọmọ Màlúù Wúrà
- A Fọ́ Àwọn Wàláà Òfin
- A Tún Àwọn Wàláà Òfin Ṣe
- 1490 ṣáájú ìbí KristiA Kọ́ Àgọ́ Ìjọsìn 1490 ṣáájú ìbí Kristi
- Àwọn Òfin fún Ẹbọ
- A Ya Aaroni Sí Mímọ́ Gẹ́gẹ́ Bí Àlùfáà
- A Pa Nadabu àti Abihu Run
- Àjọ Ìrékọjá Kejì
- Àwọn Òfin fún Ìwẹ̀nùmọ́
- Òfin Àwọn Ẹbọ fún Ètùtù
- Àwọn Òfin Onírúurú, Àwọn Òfin Ìwà, àti Àwọn Òfin Ààtò Ìsìn
- Àwọn Òfin Lórí Àjọ̀dún, Ìjẹ́jẹ̀ẹ́, Àwọn Ohun Tí A Yà Sọ́tọ̀ fún Ọlọ́run, àti Ìdámẹ́wàá
- Àwọn Ìhalẹ̀ àti Ègún Alásọtẹ́lẹ̀
- A Ka Àwọn Ènìyàn
- Àwọn Òfin fún Gbígbé Àgọ́ Ìjọsìn Kúrò
- A Dá Onírúurú Ààtò Tí Òfin Béèrè Sílẹ̀
- A Ya Àwọn Ọmọ Lefi Sí Mímọ́
- Lílo Àwọn Ìpè Fàdákà
- Bí Àwọsánmà Ṣe Darí Àwọn Ènìyàn
- Dídé Jetro
- Ìrìn Àjò Kejìlá: Láti Sinai sí Kibirotu-Hattaafa
- Ètò Ìrìn Àjò
- Jetro Padà sí Midiani
- Ìbùkún Mose Nígbà Tí Àpótí Ẹ̀rí Bá Gbé Kúrò àti Nígbà Tí Ó Bá Dúró
- Iná ní Tabera
- Àwọn Ènìyàn Kùn fún Ẹran
- Ìrìn Àjò Kẹtàlá: Láti Kibirotu-Hattaafa sí Haserotu
- Ẹ̀tẹ̀ Miriamu
- Ìrìnàjò Kẹrìnlá: Láti Haserotu sí Ritma
- 1489 ṣáájú ìbí KristiA Rán Àwọn Amí Jáde 1489 ṣáájú ìbí Kristi
- Àwọn Òfin nípa Ẹbọ àti Ẹ̀ṣẹ̀ Àìmọ̀ọ́mọ̀
- Ìṣọ̀tẹ̀ Kora, Datani àti Abiramu
- 1489 sí 1452 ṣáájú ìbí KristiÌrìnàjò Kẹ́ẹ̀dógún: Láti Ritma sí Rimoni-Peresi 1489 sí 1452 ṣáájú ìbí Kristi
- Ìrìnàjò Kẹrìndínlógún: Láti Rimoni-Peresi sí Libina
- Ìrìnàjò Kẹtàdínlógún: Láti Libina sí Rissa
- Ìrìnàjò Kejìdínlógún: Láti Rissa sí Kehelata
- Ìrìnàjò Kọkàndínlógún: Láti Kehelata sí Òkè Ṣeferi
- Ìrìnàjò Ogún: Láti Òkè Ṣeferi sí Harada
- Ìrìnàjò Kọkànlélógún: Láti Harada sí Makhelotu
- Ìrìnàjò Kejìlélógún: Láti Makhelotu sí Tahati
- Ìrìnàjò Kẹtàlélógún: Láti Tahati sí Tẹra
- Ìrìnàjò Kẹrìnlélógún: Láti Tẹra sí Mitka
- Ìrìnàjò Kẹ́ẹ̀dọ́gbọ̀n: Láti Mitka sí Haṣmona
- Ìrìnàjò Kẹrìndínlọ́gbọ̀n: Láti Haṣmona sí Moserotu
- Ìrìnàjò Kẹtàdínlọ́gbọ̀n: Láti Moserotu sí Bene-Jaakani
- Ìrìnàjò Kejìdínlọ́gbọ̀n: Láti Bene-Jaakani sí Hori-Haggidgadi
- Ìrìnàjò Kọkàndínlọ́gbọ̀n: Láti Hori-Haggidgadi sí Jotbata
- Ìrìnàjò Ọgbọ̀n: Láti Jotbata sí Abrona
- Ìrìnàjò Kọkànlélọ́gbọ̀n: Láti Abrona sí Esioni-Geberi
- Ìrìnàjò Kejìlélọ́gbọ̀n: Láti Esioni-Geberi sí Kadeṣi
- 1452 ṣáájú ìbí KristiMiriamu Kú, Àwọn Ènìyàn sì Kùn nítorí Omi 1452 ṣáájú ìbí Kristi
- Edomu Kọ̀ láti Jẹ́ kí Àwọn Ènìyàn Kọjá
- Ìṣẹ́gun lórí Aradi ará Kenaani
- Ìrìnàjò Kẹtàlélọ́gbọ̀n: Láti Kadeṣi-Barnea sí Òkè Hori
- Ikú Aaroni
- Ìrìnàjò Kẹrìnlélọ́gbọ̀n: Láti Òkè Hori sí Salmona
- A Rán Àwọn Ejò Amúná
- Ìrìnàjò Kárùndínlógójì: Láti Salmona sí Punoni
- Ìrìnàjò Kẹrìndínlógójì: Láti Punoni sí Obotu
- Ìrìnàjò Kẹtàdínlógójì: Láti Obotu sí Iye-Abarimu
- 1451 ṣáájú ìbí KristiÌrìnàjò Kejìdínlógójì: Láti Iye-Abarimu sí Diboni-Gadi 1451 ṣáájú ìbí Kristi
- Ìṣẹ́gun lórí Sihoni, Ọba Àwọn ará Amori
- Ìṣẹ́gun lórí Ogu, Ọba Baṣani
- Ìrìnàjò Kọkàndínlógójì: Láti Diboni-Gadi sí Alimon-Diblataimu
- Ìrìnàjò Ogójì: Sí Àwọn Òkè Abarimu
- Ìrìnàjò Kọkànlélógójì: Láti Abarimu sí Àwọn Pẹ̀tẹ́lẹ̀ Moabu
- Balaamu àti Balaki
- Ìrìnàjò Kejìlélógójì: Àwọn Pẹ̀tẹ́lẹ̀ Moabu
- Ìbọ̀rìṣà Baali-Peori
- Ìkànìyàn Kẹta ti Àwọn Ènìyàn
- Òfin Ogún
- Àwọn Òfin Ẹbọ
- Òfin Ẹ̀jẹ́
- Ìkógun Midiani
- Reubeni àti Gadi Gba Àwọn Agbègbè Wọn
- Àwọn Òfin fún Israẹli Lẹ́yìn Gbígba Kenaani
- Ọ̀rọ̀ Ìyànjú Ìkẹyìn Mose
- Mose Tún Òfin Ìwà Sọ
- Mose Tún Òfin Àwọn Ààtò Ìsìn Sọ
- Mose Tún Òfin Ìdájọ́ Sọ
- A Fìdí Òfin Múlẹ̀
- Àwọn Èrè àti Ìjìyà Òfin
- Ẹ̀bẹ̀ Ìparí Mose sí Àwọn Ènìyàn
- Ìparí Ìgbésí Ayé Mose
- A Kéde Ikú Mose
- A Yan Joṣua Láti Rọ́pò Mose
- Àṣẹ Ìkẹyìn Mose sí Àwọn Ènìyàn
- Àṣẹ Mose sí Joṣua
- Mose Parí Kíkọ Òfin
- Àṣẹ Kejì sí Joṣua
- Orin Mose
- Ìdágbére Mose sí Àwọn Ènìyàn
- Mose Gun Òkè Nebo Láti Kú
- Mose Súre fún Àwọn Ènìyàn
- Mose Kú, Àwọn Ènìyàn sì Ṣọ̀fọ̀
-
1451 sí 1015 ṣáájú ìbí Kristi
Àkókò 4 Láti Wíwọ Kenaani Títí Dé Ikú Dafidi
1451 sí 1015 ṣáájú ìbí Kristi-
1451 sí 1444 ṣáájú ìbí KristiApá 1: Ìṣẹ́gun Lórí Kenaani 1451 sí 1444 ṣáájú ìbí Kristi
- Iṣẹ́ tí A Yàn fún Joṣua
- Joṣua Rán Àwọn Amí Jáde
- Líla Jordani
- A Tún Májẹ̀mú Ṣe ní Kenaani
- Ìṣẹ́gun Lórí Jeriko
- Gbígba Ai
- Àwọn Ará Gibeoni, àti Ṣíṣẹ́gun Àwọn Ọba Márùn-ún
- 1445 ṣáájú ìbí KristiJoṣua Parí Ìṣẹ́gun Lórí Kenaani 1445 ṣáájú ìbí Kristi
- 1444 ṣáájú ìbí KristiẸ̀yà Reubeni àti Àwọn Mìíràn Padà sí Ilé 1444 ṣáájú ìbí Kristi
-
1444 ṣáájú ìbí KristiApá 2: Ìpín Ilẹ̀ lápapọ̀ 1444 ṣáájú ìbí Kristi
- 1443 ṣáájú ìbí KristiApá 3: Àwọn Ìyànjú Ìkẹyìn Joṣua àti Ikú Rẹ̀ 1443 ṣáájú ìbí Kristi
-
1425 sí 1413 ṣáájú ìbí KristiApá 4: Láìsí Alákòóso Lẹ́yìn Ikú Joṣua 1425 sí 1413 ṣáájú ìbí Kristi
- Israẹli Lẹ́yìn Ikú Joṣua
- Áńgẹ́lì Kan Bá Àwọn Ènìyàn Wí ní Bokimu
- 1413 ṣáájú ìbí KristiÌbọ̀rìṣà Bẹ̀rẹ̀ Láàárín àwọn ará Israẹli 1413 ṣáájú ìbí Kristi
- Ìtàn Ọmọ Lefi ti Efraimu
-
1405 sí 1116 ṣáájú ìbí KristiApá 5: Ìṣàkóso Àwọn Onídàájọ́ 1405 sí 1116 ṣáájú ìbí Kristi
- Otnieli Ṣe Onídàájọ́ Israẹli
- 1343 ṣáájú ìbí KristiEhudu Ṣe Onídàájọ́ Israẹli 1343 ṣáájú ìbí Kristi
- 1325 ṣáájú ìbí KristiṢamgari Ṣe Onídàájọ́ Israẹli 1325 ṣáájú ìbí Kristi
- 1305 ṣáájú ìbí KristiDebora Wòlíì Obìnrin Ṣe Onídàájọ́ Israẹli 1305 ṣáájú ìbí Kristi
- 1285 ṣáájú ìbí KristiOrin Debora àti Baraki 1285 ṣáájú ìbí Kristi
- 1252 ṣáájú ìbí KristiMidiani Sọ àwọn ará Israẹli Di Ẹrú 1252 ṣáájú ìbí Kristi
- 1245 ṣáájú ìbí KristiÌtàn Rutu 1245 ṣáájú ìbí Kristi
- Gideoni Ṣe Onídàájọ́ Israẹli
- Ikú Gideoni
- 1235 ṣáájú ìbí KristiAbimeleki Fi Agbára Gba Ìjọba 1235 ṣáájú ìbí Kristi
- Tola Ṣe Onídàájọ́ Israẹli
- 1210 ṣáájú ìbí KristiJairi Ṣe Onídàájọ́ Israẹli 1210 ṣáájú ìbí Kristi
- 1206 ṣáájú ìbí KristiJefta Ṣe Onídàájọ́ Israẹli 1206 ṣáájú ìbí Kristi
- 1175 ṣáájú ìbí KristiIbsani, Eloni àti Abdoni Ṣe Onídàájọ́ Israẹli 1175 ṣáájú ìbí Kristi
- 1156 ṣáájú ìbí KristiÌṣàkóso Eli àti Ìbí Samsoni 1156 ṣáájú ìbí Kristi
- 1155 ṣáájú ìbí KristiÌbí Samuẹli 1155 ṣáájú ìbí Kristi
- 1143 ṣáájú ìbí KristiÌpè Samuẹli 1143 ṣáájú ìbí Kristi
- 1136 ṣáájú ìbí KristiSamsoni Ṣe Ìgbéyàwó Ó sì Bá Àwọn Ará Filistini Jà 1136 ṣáájú ìbí Kristi
- 1117 ṣáájú ìbí KristiA Rán Wòlíì Kan sí Eli 1117 ṣáájú ìbí Kristi
- Ikú Samsoni
- 1116 ṣáájú ìbí KristiIkú Eli 1116 ṣáájú ìbí Kristi
- Àpótí ẹ̀rí lẹ́yìn tí a gbà á
- Samuẹli Ṣàkóso Israẹli
-
1095 sí 1055 ṣáájú ìbí KristiApá 6: Ìjọba Saulu 1095 sí 1055 ṣáájú ìbí Kristi
- A Fi Saulu Jọba Lórí Israẹli
- Àwọn ogun Saulu
- 1063 ṣáájú ìbí KristiA fi òróró yan Dafidi ní ìkọ̀kọ̀ 1063 ṣáájú ìbí Kristi
- Dafidi ṣẹ́gun Goliati
- Orin ìyìn kan nípa ìṣẹ́gun lórí Goliati
- Dafidi títí di ìgbà tí ó sá kúrò ní ààfin Saulu
- 1061 ṣáájú ìbí KristiDafidi sá lọ sí Rama 1061 ṣáájú ìbí Kristi
- 1060 ṣáájú ìbí KristiDafidi sá lọ sọ́dọ̀ Ahimeleki ní Nobu 1060 ṣáájú ìbí Kristi
- Dafidi sá lọ sọ́dọ̀ Akiṣi, ọba Gati
- Dafidi sá lọ sínú ihò Adullamu
- Dafidi ní Mispa
- Dafidi ní Keila
- 1059 ṣáájú ìbí KristiDafidi ní aginjù Sifi àti Maoni 1059 ṣáájú ìbí Kristi
- 1058 ṣáájú ìbí KristiDafidi ní En-Gedi 1058 ṣáájú ìbí Kristi
- 1057 ṣáájú ìbí KristiIkú Samuẹli, àti Dafidi ní Parani 1057 ṣáájú ìbí Kristi
- Dafidi ní aginjù Sifi lẹ́ẹ̀kan sí i
- 1056 ṣáájú ìbí KristiAkiṣi fi Siklagi fún Dafidi 1056 ṣáájú ìbí Kristi
- 1055 ṣáájú ìbí KristiIkú Saulu 1055 ṣáájú ìbí Kristi
- Dafidi ṣọ̀fọ̀ Saulu àti Jonatani
-
1055 sí 1015 ṣáájú ìbí KristiApá 7: Ìjọba Dafidi 1055 sí 1015 ṣáájú ìbí Kristi
- A fi Dafidi jẹ ọba ní Hebroni
- 1048 ṣáájú ìbí KristiA fi Dafidi jẹ ọba lórí gbogbo Israẹli 1048 ṣáájú ìbí Kristi
- 1047 ṣáájú ìbí KristiHiramu kí Dafidi kú oríire 1047 ṣáájú ìbí Kristi
- 1045 ṣáájú ìbí KristiA gbé àpótí ẹ̀rí lọ sí Jerusalẹmu 1045 ṣáájú ìbí Kristi
- A gbé àpótí ẹ̀rí wá láti Kiriati-Jearimu
- Orin ìyìn kan tí a kọ nígbà tí a kọ́kọ́ gbé àpótí ẹ̀rí kúrò
- Àpótí ẹ̀rí kúrò ní ilé Obedi-Edomu
- Orin ìyìn kan tí a kọ kí a tó gbé àpótí ẹ̀rí kúrò ní ẹ̀ẹ̀kejì
- Gbígbé àpótí ẹ̀rí kúrò
- 1044 ṣáájú ìbí KristiA kọ̀ fún Dafidi láti kọ́ tẹmpili 1044 ṣáájú ìbí Kristi
- 1040 ṣáájú ìbí KristiOgun pẹ̀lú àwọn orílẹ̀-èdè tí ó yí wọn ká 1040 ṣáájú ìbí Kristi
- Hadadi sá àsálà
- Oore Dafidi sí ìdílé Saulu
- 1035 ṣáájú ìbí KristiPanṣágà Dafidi 1035 ṣáájú ìbí Kristi
- Ìtàn ìdílé Dafidi
- Amnoni àti Tamari
- Ìbí Solomoni
- 1030 ṣáájú ìbí KristiIkú Amnoni 1030 ṣáájú ìbí Kristi
- 1027 ṣáájú ìbí KristiÌṣọ̀tẹ̀ Absalomu 1027 ṣáájú ìbí Kristi
- 1022 ṣáájú ìbí KristiÌṣọ̀tẹ̀ Ṣeba, àti ìyàn 1022 ṣáájú ìbí Kristi
- 1019 ṣáájú ìbí KristiOgun ìkẹyìn pẹ̀lú àwọn Filistini 1019 ṣáájú ìbí Kristi
- 1017 ṣáájú ìbí KristiDafidi ka àwọn ènìyàn 1017 ṣáájú ìbí Kristi
- 1015 ṣáájú ìbí KristiOṣù Mẹ́fà Ìkẹyìn Ìjọba Dafidi 1015 ṣáájú ìbí Kristi
- Dafidi Múra láti Kọ́ Tẹmpili
- Ìṣọ̀tẹ̀ Adonijah
- Àpéjọ Àkọ́kọ́ àwọn Ènìyàn
- Ó ṣeé ṣe gan-an kí ó jẹ́ Sáàmù kan láti ìgbà ìkẹyìn ayé Dafidi
- Ìmúrasílẹ̀ fún iṣẹ́ ìsìn Tẹmpili
- Àwọn Sáàmù Dafidi, Tí A Kò Mọ Ọjọ́ Wọn
- Àwọn Sáàmù láti Ìgbà Ìjọba Dafidi, Tí Ọjọ́ Wọn Kò Dájú
- Àpéjọ Kejì àwọn Ènìyàn
- Àṣẹ Dafidi fún Solomoni
- Àwọn Ọ̀rọ̀ Ìkẹyìn Dafidi
- Ikú Dafidi
-
-
1015 sí 975 ṣáájú ìbí Kristi
Àkókò 5 Ìjọba Solomoni
1015 sí 975 ṣáájú ìbí Kristi-
1015 sí 1011 ṣáájú ìbí KristiApá 1: Ìjọba Solomoni Ṣáájú Ìyàsímímọ́ Tẹmpili 1015 sí 1011 ṣáájú ìbí Kristi
- Ẹbọ Solomoni ní Gibeoni àti Ìdájọ́ Rẹ̀
- Solomoni Múra láti Kọ́ Tẹmpili
- 1011 ṣáájú ìbí KristiIkú Ṣimei 1011 ṣáájú ìbí Kristi
- Ìgbéyàwó Solomoni
- 1011 sí 1005 ṣáájú ìbí KristiApá 2: Kíkọ́ Tẹmpili 1011 sí 1005 ṣáájú ìbí Kristi
-
1004 ṣáájú ìbí KristiApá 3: Ìyàsímímọ́ Tẹmpili 1004 ṣáájú ìbí Kristi
-
1004 sí 1001 ṣáájú ìbí KristiApá 4: Àwọn Ilé Mìíràn àti Ọláńlá Solomoni 1004 sí 1001 ṣáájú ìbí Kristi
- Ọlọ́run Farahàn Solomoni
- 1001 ṣáájú ìbí KristiÀwọn Ìṣẹ́gun Ilẹ̀ àti Ìṣe Mìíràn Solomoni 1001 ṣáájú ìbí Kristi
- Orin Solomoni
- 992 ṣáájú ìbí KristiApá 5: Ayaba Ṣeba Ṣèbẹ̀wò sí Solomoni 992 ṣáájú ìbí Kristi
-
992 sí 984 ṣáájú ìbí KristiApá 6: Ọgbọ́n Solomoni 992 sí 984 ṣáájú ìbí Kristi
- Ọgbọ́n àti Òkìkí Solomoni
- 984 ṣáájú ìbí KristiÀwọn Òwe 984 ṣáájú ìbí Kristi
- Ẹ̀kọ́ Bàbá Nípa Ọgbọ́n
- Àwọn Òwe Solomoni
- Àwọn Ọ̀rọ̀ Àwọn Ọlọ́gbọ́n
- Àwọn Òwe Solomoni Mìíràn
- Àwọn Ọ̀rọ̀ Aguri àti Ọba Lemueli
- 980 sí 975 ṣáájú ìbí KristiApá 7: Ẹ̀ṣẹ̀ Solomoni 980 sí 975 ṣáájú ìbí Kristi
- 975 ṣáájú ìbí KristiApá 8: Ikú Solomoni 975 ṣáájú ìbí Kristi
-
-
975 sí 606 ṣáájú ìbí Kristi
Àkókò 6 Láti Rehoboamu dé Ìgbèkùn ní Babeli
975 sí 606 ṣáájú ìbí Kristi-
975 sí 970 ṣáájú ìbí KristiApá 1: Ìjọba Rehoboamu 975 sí 970 ṣáájú ìbí Kristi
- Ìjọba Juda
- Àwọn Ẹ̀yà Mẹ́wàá Ṣọ̀tẹ̀
- 973 ṣáájú ìbí KristiRehoboamu Ṣàkóso Juda 973 ṣáájú ìbí Kristi
- 970 ṣáájú ìbí KristiṢiṣaki Gbé Ogun Wọ Juda 970 ṣáájú ìbí Kristi
- Ìjọba Israẹli
- 974 ṣáájú ìbí KristiÌbọ̀rìṣà àwọn ẹgbọrọ màlúù wúrà 974 ṣáájú ìbí Kristi
- Ìtàn wòlíì Beteli
- 958 ṣáájú ìbí KristiApá 2: Ìjọba Abijah 958 ṣáájú ìbí Kristi
-
955 sí 925 ṣáájú ìbí KristiApá 3: Ìjọba Asa 955 sí 925 ṣáájú ìbí Kristi
- Ìjọba Juda
- Ìfọkànsìn Asa sí Ọlọ́run
- Asa bá Ọlọ́run dá májẹ̀mú
- Ogun Asa pẹ̀lú Baaṣa
- Ikú Asa
- Ìjọba Israẹli
- Ikú Jeroboamu àti ọmọ rẹ̀
- 953 ṣáájú ìbí KristiÌjọba Nadabu 953 ṣáájú ìbí Kristi
- 930 ṣáájú ìbí KristiÌjọba Baaṣa 930 ṣáájú ìbí Kristi
- Ìjọba Ela
- Ìjọba Simri
- 925 ṣáájú ìbí KristiÌjọba Omri 925 ṣáájú ìbí Kristi
- Ahabu bẹ̀rẹ̀ sí í jọba
-
914 sí 892 ṣáájú ìbí KristiApá 4: Ìjọba Jehoṣafati 914 sí 892 ṣáájú ìbí Kristi
- Ìjọba Juda
- Ìgorí ìtẹ́ àti ìjọba rere Jehoṣafati
- 897 ṣáájú ìbí KristiÀwọn ogun àti ìṣàkóso rere Jehoṣafati 897 ṣáájú ìbí Kristi
- Ikú Jehoṣafati
- Ìjọba Israẹli
- 908 ṣáájú ìbí KristiElijah sọ àsọtẹ́lẹ̀ ọ̀dá 908 ṣáájú ìbí Kristi
- 906 ṣáájú ìbí KristiElijah fi ẹ̀rí iṣẹ́ ìránṣẹ́ rẹ̀ hàn, ó sì sá fún Jesebeli 906 ṣáájú ìbí Kristi
- Ìpè Eliṣa
- 901 ṣáájú ìbí KristiBeni-Hadadi dó ti Samaria 901 ṣáájú ìbí Kristi
- 900 ṣáájú ìbí KristiÌṣẹ́gun kejì lórí àwọn ará Aramu 900 ṣáájú ìbí Kristi
- 899 ṣáájú ìbí KristiA gba ọgbà àjàrà Naboti 899 ṣáájú ìbí Kristi
- 897 ṣáájú ìbí KristiIkú Ahabu 897 ṣáájú ìbí Kristi
- Ìjọba àti ikú Ahasiah
- Jehoramu jọba, Moabu sì ṣọ̀tẹ̀
- 896 ṣáájú ìbí KristiA gbé Elijah lọ sí ọ̀run 896 ṣáájú ìbí Kristi
- 895 ṣáájú ìbí KristiJehoramu ṣẹ́gun àwọn ará Moabu 895 ṣáájú ìbí Kristi
- 892 ṣáájú ìbí KristiÀwọn iṣẹ́ ìyanu Eliṣa 892 ṣáájú ìbí Kristi
-
889 sí 887 ṣáájú ìbí KristiApá 5: Ìjọba Jehoramu 889 sí 887 ṣáájú ìbí Kristi
- Ìjọba Juda
- Ìjọba Israẹli
- 887 ṣáájú ìbí KristiÌjọba Jehoramu lórí Israẹli ń bá a lọ 887 ṣáájú ìbí Kristi
- Ìdótì àti ìyàn Samaria
-
885 sí 884 ṣáájú ìbí KristiApá 6: Ìjọba Ahasiah 885 sí 884 ṣáájú ìbí Kristi
- Ìjọba Juda
- Ìjọba Israẹli
- 885 ṣáájú ìbí KristiÌjọba Jehoramu lórí Israẹli parí 885 ṣáájú ìbí Kristi
- Ìdìtẹ̀ Hasaeli
- 884 ṣáájú ìbí KristiÌdìtẹ̀ Jehu 884 ṣáájú ìbí Kristi
- Ikú Jehoramu
- Jehu jọba, Jesebeli sì kú
- Ikú àwọn ọmọ Ahabu
- Ikú àwọn ìbátan Ahasiah
- Ikú àwọn àlùfáà Baali
-
884 ṣáájú ìbí KristiApá 7: Ìjọba Ataliah 884 ṣáájú ìbí Kristi
-
878 sí 838 ṣáájú ìbí KristiApá 8: Ìjọba Joaṣi 878 sí 838 ṣáájú ìbí Kristi
- Ìjọba Juda
- Ìbẹ̀rẹ̀ ìjọba Joaṣi
- 856 ṣáájú ìbí KristiA tún tẹmpili ṣe 856 ṣáájú ìbí Kristi
- 840 ṣáájú ìbí KristiJoaṣi Yẹ̀ Kúrò nínú Ìgbàgbọ́, Ó sì Kú 840 ṣáájú ìbí Kristi
- Ìjọba Israẹli
- 838 ṣáájú ìbí KristiIkú Jehu 838 ṣáájú ìbí Kristi
- 849 ṣáájú ìbí KristiÌjọba Jehoahasi ti Israẹli 849 ṣáájú ìbí Kristi
- Jehoaṣi Jọba, Eliṣa sì Kú
-
838 sí 810 ṣáájú ìbí KristiApá 9: Ìjọba Amasiah 838 sí 810 ṣáájú ìbí Kristi
- Ìjọba Juda
- Amasiah Fìyà Jẹ Àwọn Apànìyàn Baba Rẹ̀
- 827 ṣáájú ìbí KristiOgun Amasiah pẹ̀lú Edomu 827 ṣáájú ìbí Kristi
- 826 ṣáájú ìbí KristiOgun Amasiah pẹ̀lú Israẹli 826 ṣáájú ìbí Kristi
- 810 ṣáájú ìbí KristiIkú Amasiah 810 ṣáájú ìbí Kristi
- Ìjọba Israẹli
- Ìjọba Jehoaṣi Tẹ̀ Síwájú
- Ìjọba Jeroboamu Kejì
-
810 sí 758 ṣáájú ìbí KristiApá 10: Ìjọba Ussiah 810 sí 758 ṣáájú ìbí Kristi
- Ìjọba Juda
- Ìbẹ̀rẹ̀ Ìjọba Ussiah àti Aásìkí Rẹ̀
- ní nǹkan bí 787 ṣáájú ìbí KristiJoẹli Sọtẹ́lẹ̀ Ìṣubú Juda ní nǹkan bí 787 ṣáájú ìbí Kristi
- 787 tàbí 765 ṣáájú ìbí KristiA Fi Ẹ̀tẹ̀ Kọlu Ussiah 787 tàbí 765 ṣáájú ìbí Kristi
- 758 ṣáájú ìbí KristiA Yan Isaiah sí Ipò Wòlíì 758 ṣáájú ìbí Kristi
- Ikú Ussiah
- Ìjọba Israẹli
- 809 ṣáájú ìbí KristiÌparí Ìjọba Jeroboamu Kejì 809 ṣáájú ìbí Kristi
- 801 ṣáájú ìbí KristiHosea Sọtẹ́lẹ̀ sí Israẹli 801 ṣáájú ìbí Kristi
- 793 ṣáájú ìbí KristiAmosi Sọtẹ́lẹ̀ Lòdì sí Àwọn Orílẹ̀-Èdè àti Israẹli 793 ṣáájú ìbí Kristi
- ní nǹkan bí 787 ṣáájú ìbí KristiÌtàn Jona ní nǹkan bí 787 ṣáájú ìbí Kristi
- 784 ṣáájú ìbí KristiIkú Jeroboamu Kejì 784 ṣáájú ìbí Kristi
- 776 ṣáájú ìbí KristiIsraẹli Láìsí Ọba Lẹ́yìn Ikú Jeroboamu Kejì 776 ṣáájú ìbí Kristi
- 773 ṣáájú ìbí KristiÌjọba Sekariah 773 ṣáájú ìbí Kristi
- 772 ṣáájú ìbí KristiÌjọba Ṣallumu 772 ṣáájú ìbí Kristi
- Ìjọba Menahemu
- 768 ṣáájú ìbí KristiÌjọba Pekahiah 768 ṣáájú ìbí Kristi
-
758 ṣáájú ìbí KristiApá 11: Ìjọba Jotamu 758 ṣáájú ìbí Kristi
-
742 sí 726 ṣáájú ìbí KristiApá 12: Ìjọba Ahasi 742 sí 726 ṣáájú ìbí Kristi
- Ìjọba Juda
- Ìwà Ahasi
- Resini àti Peka Gbé Ogun Wọ Juda
- Isaiah Sọtẹ́lẹ̀ Ìparun Damasku àti Ẹ̀yà Mẹ́wàá
- 741 ṣáájú ìbí KristiPeka Pa Juda Run 741 ṣáájú ìbí Kristi
- 740 ṣáájú ìbí KristiAhasi Bá Tiglat-Pileseri Ṣe Àjọṣepọ̀ 740 ṣáájú ìbí Kristi
- 726 ṣáájú ìbí KristiAhasi Kú; A Sọtẹ́lẹ̀ Agbára Hesekiah 726 ṣáájú ìbí Kristi
- Ìjọba Israẹli
- 739 ṣáájú ìbí KristiÌjọba Peka àti Hosea 739 ṣáájú ìbí Kristi
-
726 sí 699 ṣáájú ìbí KristiApá 13: Ìjọba Hesekiah 726 sí 699 ṣáájú ìbí Kristi
- Ìjọba Juda
- Hesekiah Ṣe Àtúnṣe sí Ìjọsìn
- Isaiah Sọtẹ́lẹ̀ Ìparun Moabu
- 722 ṣáájú ìbí KristiÀwọn Àsọtẹ́lẹ̀ Mika Ṣe Àtìlẹ́yìn fún Àtúnṣe Hesekiah 722 ṣáájú ìbí Kristi
- 721 ṣáájú ìbí KristiIsaiah Sọtẹ́lẹ̀ Ìjìyà Ejibiti àti Ìyípadà Rẹ̀ sí Ọlọ́run 721 ṣáájú ìbí Kristi
- 720 ṣáájú ìbí KristiNahumu Sọtẹ́lẹ̀ Lòdì sí Ninefe 720 ṣáájú ìbí Kristi
- 715 ṣáájú ìbí KristiIsaiah Sọ Ìparun Tire Tẹ́lẹ̀ 715 ṣáájú ìbí Kristi
- Isaiah Sọtẹ́lẹ̀ Nípa Ìkọlù Àwọn Ará Asiria
- 714 ṣáájú ìbí KristiÀsọtẹ́lẹ̀ Nípa Ìdahoro àti Ìmúpadàbọ̀sípò Judea 714 ṣáájú ìbí Kristi
- 713 ṣáájú ìbí KristiÀsọtẹ́lẹ̀ Nípa Ìkọlù Judea àti Ìparun Babeli 713 ṣáájú ìbí Kristi
- Ìkọlù Àkọ́kọ́ Sennakeribu
- Hesekiah Juwọ́ Sílẹ̀, A sì Gba Aṣdodu
- Ìpè Àsọtẹ́lẹ̀ sí Jerusalẹmu
- Àìsàn Hesekiah
- Ọba Babeli Kí Hesekiah Kú Oríire
- 710 ṣáájú ìbí KristiÌkọlù Kejì Sennakeribu ní Ṣókí 710 ṣáájú ìbí Kristi
- Ìkọlù Kejì Sennakeribu ní Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́
- A Pa Ẹgbẹ́ Ọmọ Ogun Sennakeribu Run
- 710 sí 699 ṣáájú ìbí KristiA Ṣèlérí Ìtùnú fún Àwọn Ènìyàn Ọlọ́run 710 sí 699 ṣáájú ìbí Kristi
- Àsọtẹ́lẹ̀ Nípa Wíwá Kristi
- 710 ṣáájú ìbí KristiÌwà Òmùgọ̀ Ìbọ̀rìṣà àti Ìyípadà Àwọn Kèfèrí 710 ṣáájú ìbí Kristi
- Àsọtẹ́lẹ̀ Nípa Ìgbèkùn àti Ìparun Babeli
- Ìbáwí fún Ìbọ̀rìṣà
- Messia Bá Àwọn Ènìyàn Rẹ̀ Sọ̀rọ̀
- Àsọtẹ́lẹ̀ Nípa Kíkọ Kristi Sílẹ̀
- Àsọtẹ́lẹ̀ Nípa Ìrẹ̀sílẹ̀ àti Ìgbéga Kristi
- Àsọtẹ́lẹ̀ Nípa Ìdàgbàsókè àti Ìṣẹ́gun Ìjọ
- Ọ̀pọ̀ Ìbùkún Ìhìnrere
- Àsọtẹ́lẹ̀ Àjálù Nítorí Ìbọ̀rìṣà Judea
- Ògo àti Ìṣẹ́gun Ìjọ ní Ọjọ́ Iwájú
- Ikú Hesekiah
- Ìjọba Israẹli
- ní nǹkan bí 725 ṣáájú ìbí KristiṢalamaneseri Gbógun Wọ Ìjọba Hosea ní nǹkan bí 725 ṣáájú ìbí Kristi
- 725 ṣáájú ìbí KristiHosea Sọ Ìgbèkùn Ẹ̀yà Mẹ́wàá Tẹ́lẹ̀ 725 ṣáájú ìbí Kristi
- 723 ṣáájú ìbí KristiA Kó Ẹ̀yà Mẹ́wàá Lọ sí Ìgbèkùn 723 ṣáájú ìbí Kristi
-
698 sí 676 ṣáájú ìbí KristiApá 14: Ìṣàkóso Manase 698 sí 676 ṣáájú ìbí Kristi
- Ìjọba Juda
- Ìbọ̀rìṣà Manase
- Isaiah Sọ Ìgbèkùn Ṣebna Tẹ́lẹ̀
- 676 ṣáájú ìbí KristiÌgbèkùn àti Ikú Manase 676 ṣáájú ìbí Kristi
- Àwọn Ilẹ̀ Ẹ̀yà Mẹ́wàá Tẹ́lẹ̀
- 643 ṣáájú ìbí KristiApá 15: Ìjọba Amoni 643 ṣáájú ìbí Kristi
-
641 sí 610 ṣáájú ìbí KristiApá 16: Ìjọba Josiah 641 sí 610 ṣáájú ìbí Kristi
- Josiah Mú Ìbọ̀rìṣà Kúrò
- 629 ṣáájú ìbí KristiA Yan Jeremiah sí Ipò Wòlíì 629 ṣáájú ìbí Kristi
- 624 ṣáájú ìbí KristiJosiah Tún Tẹmpili Ṣe 624 ṣáájú ìbí Kristi
- Sefaniah Rọ Àwọn Ènìyàn láti Ronúpìwàdà
- Àtúnṣe Ẹ̀sìn Josiah
- 623 ṣáájú ìbí KristiJosiah Ṣe Àjọ Ìrékọjá 623 ṣáájú ìbí Kristi
- 612 ṣáájú ìbí KristiJeremiah Bá Àwọn Ènìyàn Wí fún Ìfàsẹ́yìn Wọn 612 ṣáájú ìbí Kristi
- Jeremiah Rí Ìbànújẹ́ Ìgbèkùn Ṣáájú
- Habakuku Sọ Àsọtẹ́lẹ̀ Ìjìyà fún Ìfàsẹ́yìn
- Jeremiah Pe fún Ìrònúpìwàdà, Ó sì Ṣọ̀fọ̀
- 610 ṣáájú ìbí KristiA Rán Àwọn Ènìyàn Létí Májẹ̀mú Josiah 610 ṣáájú ìbí Kristi
- Ikú Josiah
- 610 ṣáájú ìbí KristiApá 17: Ìjọba Jehoahasi 610 ṣáájú ìbí Kristi
-
610 sí 606 ṣáájú ìbí KristiApá 18: Ìjọba Jehoiakimu 610 sí 606 ṣáájú ìbí Kristi
- Jehoiakimu Di Ọba
- 609 ṣáájú ìbí KristiÀwọn Ìkìlọ̀ pé Ìgbèkùn Dájú 609 ṣáájú ìbí Kristi
- Àsọtẹ́lẹ̀ Ohun Tí Yóò Ṣẹlẹ̀ sí Paṣuri
- Àsọtẹ́lẹ̀ Ohun Tí Yóò Ṣẹlẹ̀ sí Ṣallumu àti Jehoiakimu
- A Mú Jeremiah, A sì Fi Ẹ̀sùn Kàn Á
- 606 ṣáájú ìbí KristiJeremiah Sọ Àsọtẹ́lẹ̀ Lòdì sí Ẹgbẹ́ Ọmọ Ogun Neko 606 ṣáájú ìbí Kristi
- Àwọn ọmọ Rekabu Sá sí Jerusalẹmu fún Ààbò
- Àsọtẹ́lẹ̀ Àádọ́rin Ọdún Ìgbèkùn
- Kíkà Àkọ́kọ́ tí Baruku Ka Àkájọ Ìwé
- A Tu Baruku Nínú Lẹ́yìn Kíkà Àkájọ Ìwé
- Ìgbèkùn Bẹ̀rẹ̀
-
-
606 sí 536 ṣáájú ìbí Kristi
Àkókò 7 Ìgbèkùn ní Babeli
606 sí 536 ṣáájú ìbí Kristi-
605 sí 588 ṣáájú ìbí KristiApá 1: Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ ní Jerusalẹmu Títí Tẹmpili Fi Jóná 605 sí 588 ṣáájú ìbí Kristi
- A Ka Àkájọ Ìwé fún Ìgbà Kejì
- 603 ṣáájú ìbí KristiJehoiakimu Ṣọ̀tẹ̀, Ó sì Kú 603 ṣáájú ìbí Kristi
- Ìjọba Jehoiakini àti Ìgbèkùn Esekiẹli
- 599 ṣáájú ìbí KristiSedekiah Di Ọba 599 ṣáájú ìbí Kristi
- 597 ṣáájú ìbí KristiÀsọtẹ́lẹ̀ Bí Ìgbèkùn Yóò Ti Pẹ́ Tó 597 ṣáájú ìbí Kristi
- Àsọtẹ́lẹ̀ Ìmúpadàbọ̀sípò Àwọn Júù
- 595 ṣáájú ìbí KristiA Fi Ìyà Jẹ Hananiah Wòlíì Èké 595 ṣáájú ìbí Kristi
- Àsọtẹ́lẹ̀ Nípa Àyànmọ́ Àwọn Orílẹ̀-Èdè Àyíká
- Jeremiah Sọ Àsọtẹ́lẹ̀ Lòdì sí Babeli
- Ọ̀rọ̀ Ìṣáájú sí Ìparun Jerusalẹmu
- 590 ṣáájú ìbí KristiÀwọn ará Babeli Ń Sún Mọ́lé; A Dá Àwọn Ẹrú Heberu Sílẹ̀ 590 ṣáájú ìbí Kristi
- 589 ṣáájú ìbí KristiA Fi Jeremiah Sẹ́wọ̀n 589 ṣáájú ìbí Kristi
- Àwọn ará Babeli Jáwọ́ nínú Ìsàgatì Jerusalẹmu
- Àsọtẹ́lẹ̀ Ìparun fún Àwọn Filistini àti Àwọn ará Ejibiti
- A Tún Mú Àwọn Ẹrú Heberu Padà
- A Tún Fi Jeremiah Sẹ́wọ̀n
- 588 ṣáájú ìbí KristiJeremiah Tún Àwọn Àsọtẹ́lẹ̀ Rẹ̀ Sọ fún Ọba 588 ṣáájú ìbí Kristi
- A Fi Jeremiah Sẹ́wọ̀n nínú Ẹ̀wọ̀n Abẹ́ Ilẹ̀ Malkiah
- A Gba Jerusalẹmu, A Mú Sedekiah; A Dá Jeremiah Sílẹ̀
- A Sun Tẹmpili ní Jerusalẹmu
- Jeremiah Ṣọ̀fọ̀ Ìdahoro Orílẹ̀-Èdè Rẹ̀
-
606 sí 588 ṣáájú ìbí KristiApá 2: Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ ní Babeli Títí dé Ìparun Tẹmpili 606 sí 588 ṣáájú ìbí Kristi
- Bí Nǹkan Ṣe Rí fún Daniẹli àti Àwọn Ẹlẹgbẹ́ Rẹ̀ ní Babeli
- 595 ṣáájú ìbí KristiA Yan Esekiẹli fún Iṣẹ́ 595 ṣáájú ìbí Kristi
- Àsọtẹ́lẹ̀ Nípa Àwọn Ìpọ́njú àti Ìparun Jerusalẹmu
- 594 ṣáájú ìbí KristiÌran Àwọn Ìbọ̀rìṣà Tí Ó Fa Ìgbèkùn 594 ṣáájú ìbí Kristi
- Àwọn Àsọtẹ́lẹ̀ Lòdì sí Sedekiah àti Àwọn Wòlíì Èké
- 593 ṣáájú ìbí KristiÀwọn Àsọtẹ́lẹ̀ sí Àwọn Àgbà Júù 593 ṣáájú ìbí Kristi
- 591 ṣáájú ìbí KristiÀsọtẹ́lẹ̀ Ìparun Jerusalẹmu Bí Ìsàgatì Ṣe Bẹ̀rẹ̀ 591 ṣáájú ìbí Kristi
- 589 ṣáájú ìbí KristiEsekiẹli Sọ Àsọtẹ́lẹ̀ Lòdì sí Farao àti Ejibiti 589 ṣáájú ìbí Kristi
- 588 ṣáájú ìbí KristiEsekiẹli: Ejibiti Yóò Ṣubú Bí Asiria 588 ṣáájú ìbí Kristi
-
588 sí 587 ṣáájú ìbí KristiApá 3: Àwọn Júù Tí A Kò Kó Lọ sí Babeli 588 sí 587 ṣáájú ìbí Kristi
- Àkọsílẹ̀ Ṣókí Nípa Apá Yìí
- A Fi Gedaliah Ṣe Gómìnà Judea
- Iṣmaeli Dìtẹ̀ sí Gedaliah
- 587 ṣáájú ìbí KristiJohanani Gba Àwọn Ìgbèkùn Sílẹ̀, Ó sì Sá Lọ sí Ejibiti 587 ṣáájú ìbí Kristi
- Jeremiah Sọ Àsọtẹ́lẹ̀ Lòdì sí Ejibiti
- Àwọn Àsọtẹ́lẹ̀ Ìkẹyìn Jeremiah Lòdì sí Àwọn Abọ̀rìṣà
- Àtúnsọ Àwọn Ìgbà Tí Nebukadnessari Kó Àwọn Júù Lọ ní Ìgbèkùn
-
587 sí 536 ṣáájú ìbí KristiApá 4: Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ ní Babeli Títí dé Ìpadàbọ̀ 587 sí 536 ṣáájú ìbí Kristi
- Esekiẹli Gbọ́ Nípa Ìṣubú Jerusalẹmu
- Ìparun Tire
- Ẹkún Esekiẹli fún Farao
- Esekiẹli: Ejibiti Sọ̀kalẹ̀ Sínú Ọ̀gbun
- Ẹ̀bẹ̀ sí Àwọn Ìgbèkùn ní Babeli
- Esekiẹli Dá Àwọn Alákòóso Tí Ó Ṣì Àwọn Ènìyàn Lọ́nà Lẹ́bi
- Ìjàkadì Ńlá Ìjọ pẹ̀lú Àwọn Ọ̀tá Rẹ̀
- 574 ṣáájú ìbí KristiÌran Esekiẹli Nípa Tẹmpili Kejì 574 ṣáájú ìbí Kristi
- 572 ṣáájú ìbí KristiÀsọtẹ́lẹ̀ Ìkẹyìn Esekiẹli Lòdì sí Ejibiti 572 ṣáájú ìbí Kristi
- 570 ṣáájú ìbí KristiDaniẹli Sọ Àlá Tí Nebukadnessari Ti Gbàgbé fún Un 570 ṣáájú ìbí Kristi
- Nebukadnessari Gbé Ère Wúrà Kalẹ̀
- 562 ṣáájú ìbí KristiÀlá Kejì Nebukadnessari 562 ṣáájú ìbí Kristi
- Wèrè Nebukadnessari àti Ìmúláradá Rẹ̀
- 561 ṣáájú ìbí KristiA Tú Jehoiakini Sílẹ̀ Kúrò Nínú Ẹ̀wọ̀n 561 ṣáájú ìbí Kristi
- 541 ṣáájú ìbí KristiÌran Àkọ́kọ́ Daniẹli: Àwọn Ẹranko Mẹ́rin 541 ṣáájú ìbí Kristi
- 539 ṣáájú ìbí KristiÀwọn Sáàmù Ìdààmú, Ní Pàtàkì Láti Àkókò Ìgbèkùn 539 ṣáájú ìbí Kristi
- Àsè Belṣassari
- Ìran Daniẹli nípa Àgbò àti Òbúkọ
- 538 ṣáájú ìbí KristiÀdúrà Daniẹli àti Àádọ́rin Ọ̀sẹ̀ 538 ṣáájú ìbí Kristi
- 537 ṣáájú ìbí KristiA Ju Daniẹli Sínú Ihò Àwọn Kìnnìún 537 ṣáájú ìbí Kristi
- 536 ṣáájú ìbí KristiKirusi Pa Àṣẹ Ìmúpadàbọ̀sípò Àwọn Júù 536 ṣáájú ìbí Kristi
-
-
536 sí 300 ṣáájú ìbí Kristi
Àkókò 8 Láti Ìpadàbọ̀ Títí Dé Ìparí Àkójọpọ̀ Ìwé Mímọ́
536 sí 300 ṣáájú ìbí Kristi-
536 sí 515 ṣáájú ìbí KristiApá 1: Láti Àṣẹ Kirusi Títí Dé Ìyàsímímọ́ Tẹmpili 536 sí 515 ṣáájú ìbí Kristi
- Àwọn Júù Padà Láti Ìgbèkùn
- A Fi Ìpìlẹ̀ Tẹmpili Lélẹ̀
- Iṣẹ́ Tẹmpili Dúró; Ìran Ìkẹyìn Daniẹli
- 520 ṣáájú ìbí KristiIṣẹ́ Tẹmpili Tún Bẹ̀rẹ̀ 520 ṣáájú ìbí Kristi
- 519 ṣáájú ìbí KristiA Dá Iṣẹ́ Tẹmpili Dúró, A sì Tún Bẹ̀rẹ̀ Rẹ̀ 519 ṣáájú ìbí Kristi
- 515 ṣáájú ìbí KristiA Ya Tẹmpili Kejì sí Mímọ́ 515 ṣáájú ìbí Kristi
-
486 sí 453 ṣáájú ìbí KristiApá 2: Láti Ìyàsímímọ́ Tẹmpili Títí Dé Ikú Hamani 486 sí 453 ṣáájú ìbí Kristi
- Àtakò sí Àwọn Júù Lábẹ́ Ìjọba Ahaswerusi
- 464 ṣáájú ìbí KristiÀtakò sí Àwọn Júù Lábẹ́ Ìjọba Artasasta 464 ṣáájú ìbí Kristi
- 462 ṣáájú ìbí KristiArtasasta Kọ Ayaba Rẹ̀ Sílẹ̀ 462 ṣáájú ìbí Kristi
- 458 ṣáájú ìbí KristiA Yan Esra fún Iṣẹ́ 458 ṣáájú ìbí Kristi
- Esteri Di Ayaba Persia
- 457 ṣáájú ìbí KristiÀwọn Àtúnṣe Esra 457 ṣáájú ìbí Kristi
- Àwọn Àsọtẹ́lẹ̀ Ìkẹyìn Sekariah
- Mordekai Tú Àdìtẹ̀ sí Artasasta síta
- 453 ṣáájú ìbí KristiA Borí Àdìtẹ̀ Hamani 453 ṣáájú ìbí Kristi
-
445 sí 300 ṣáájú ìbí KristiApá 3: Láti Àtúnṣe Nehemiah sí Ìparí Àkójọpọ̀ Ìwé Mímọ́ 445 sí 300 ṣáájú ìbí Kristi
- Iṣẹ́ Àkọ́kọ́ Tí A Yàn fún Nehemiah
- A Tún Àwọn Ògiri Jerusalẹmu Kọ́
- A Ya Ògiri Jerusalẹmu sí Mímọ́
- Nehemiah Padà sí Persia
- 444 sí 433 ṣáájú ìbí KristiIṣẹ́ Kejì Tí A Yàn fún Nehemiah àti Àwọn Àtúnṣe Rẹ̀ 444 sí 433 ṣáájú ìbí Kristi
- Malaki Sọ Àsọtẹ́lẹ̀ Lòdì sí Ìwà Ìbàjẹ́
- 428 sí 409 ṣáájú ìbí KristiÀwọn Àtúnṣe Síwájú Sí i Tí Nehemiah Ṣe 428 sí 409 ṣáájú ìbí Kristi
- ní nǹkan bí 400 ṣáájú ìbí KristiÀsọtẹ́lẹ̀ Ìkẹyìn ti Májẹ̀mú Láéláé ní nǹkan bí 400 ṣáájú ìbí Kristi
- ní nǹkan bí 300 ṣáájú ìbí KristiÀwọn ìtàn ìran, ìrọ́pò àti ìṣẹ̀lẹ̀ lọ́tọ̀ọ̀tọ̀ ní nǹkan bí 300 ṣáájú ìbí Kristi
-
-
7 ṣáájú ìbí Kristi sí 30 lẹ́yìn ìbí Kristi
Àwọn Ìhìnrere
7 ṣáájú ìbí Kristi sí 30 lẹ́yìn ìbí Kristi- Apá 1: Àwọn Orísun Àwọn Ìwé Ìhìnrere
- Apá 2: Wíwà Kristi Ṣáájú Ìbí Rẹ̀ àti Dídi Ẹran Ara Rẹ̀
- Apá 3: Àwọn Ìtàn Ìran Méjì nínú Matiu àti Luku
-
7 ṣáájú ìbí Kristi sí 7 lẹ́yìn ìbí KristiApá 4: Ìbí àti Ìgbà Èwe Johanu àti Jesu 7 ṣáájú ìbí Kristi sí 7 lẹ́yìn ìbí Kristi
- 7 ṣáájú ìbí KristiÁńgẹ́lì Kan Sọ fún Sekariah nípa Ìbí Johanu 7 ṣáájú ìbí Kristi
- 7 tàbí 6 ṣáájú ìbí KristiÁńgẹ́lì Kan Sọ fún Maria Wúńdíá nípa Ìbí Jesu 7 tàbí 6 ṣáájú ìbí Kristi
- Elisabeti Kọrin sí Maria nígbà Ìbẹ̀wò Rẹ̀
- Maria Kọ Orin Magnificat
- Ìbí Johanu, Ìgbà Èwe Rẹ̀, àti Ìgbésí Ayé Rẹ̀ nínú Aṣálẹ̀
- Áńgẹ́lì Kan Sọ fún Josẹfu nípa Ìbí Jesu
- 6 tàbí 5 ṣáájú ìbí KristiÌbí Jesu 6 tàbí 5 ṣáájú ìbí Kristi
- Àwọn Áńgẹ́lì Yin, Àwọn Olùṣọ́ Àgùntàn sì Júbà
- Ìkọlà Jesu
- A Fi Jesu Hàn nínú Tẹmpili
- Àwọn amòye Ṣèbẹ̀wò sí Ọba Àwọn Júù Tí A Ṣẹ̀ṣẹ̀ Bí
- 5 ṣáájú ìbí KristiA Gbé Jesu Lọ sí Ejibiti, A sì Pa Àwọn Ọmọ Bẹtilẹhẹmu 5 ṣáájú ìbí Kristi
- 4 ṣáájú ìbí KristiA Mú Jesu Láti Ejibiti Wá sí Nasareti 4 ṣáájú ìbí Kristi
- 4 ṣáájú ìbí Kristi sí 7 lẹ́yìn ìbí KristiÌgbà Èwe Jesu ní Nasareti 4 ṣáájú ìbí Kristi sí 7 lẹ́yìn ìbí Kristi
- 7 tàbí 8 lẹ́yìn ìbí KristiỌmọkùnrin Náà Jesu Ṣèbẹ̀wò sí Jerusalẹmu Ní Ọmọ Ọdún Méjìlá 7 tàbí 8 lẹ́yìn ìbí Kristi
- 6 sí 26 lẹ́yìn ìbí KristiỌdún Méjìdínlógún ní Nasareti 6 sí 26 lẹ́yìn ìbí Kristi
-
25 lẹ́yìn ìbí KristiApá 5: Johanu onítẹ̀bọmi Bẹ̀rẹ̀ Iṣẹ́ Ìránṣẹ́ Rẹ̀ 25 lẹ́yìn ìbí Kristi
-
26 àti 27 lẹ́yìn ìbí KristiApá 6: Kristi Bẹ̀rẹ̀ Iṣẹ́ Ìránṣẹ́ Rẹ̀ ní Gbangba: Ọdún Àìlókìkí 26 àti 27 lẹ́yìn ìbí Kristi
- 26 lẹ́yìn ìbí KristiJohanu Tẹ Jesu Bọmi ní Jordani 26 lẹ́yìn ìbí Kristi
- Àwọn Ìdánwò Mẹ́ta ti Jesu
- Johanu jẹ́rìí fún àwọn aṣojú ìgbìmọ̀
- Johanu Fi Jesu Hàn gẹ́gẹ́ bí Messia
- Jesu Jèrè Àwọn Ọmọ Ẹ̀yìn Rẹ̀ Àkọ́kọ́
- Jesu Ṣe Iṣẹ́ Ìyanu Rẹ̀ Àkọ́kọ́
- Ìdúró Àkọ́kọ́ Jesu ní Kapernaumu
- 27 lẹ́yìn ìbí KristiJesu Wẹ Tẹmpili Mọ́ fún Ìgbà Àkọ́kọ́ ní Àjọ̀dún ìrékọjá 27 lẹ́yìn ìbí Kristi
- Nikodemu Pàdé Jesu
- Jesu àti Johanu Ṣe Iṣẹ́ Ìránṣẹ́ Lẹ́gbẹ̀ẹ́ Ara Wọn
- Ìdí tí Kristi Fi Kúrò ní Judea
- Jesu ní Samaria
- Jesu Dé Galili
-
27 sí 29 lẹ́yìn ìbí KristiApá 7: Iṣẹ́ Ìránṣẹ́ Ńlá ní Galili 27 sí 29 lẹ́yìn ìbí Kristi
- Lẹ́yìn tí a kọ̀ ọ́ ní Nasareti, Jesu Ṣí Lọ sí Kapernaumu
- Jesu Kọ́ni ní Galili
- Ní Kana Jesu Wo Ọmọ Ọ̀gá Kan Sàn
- Nasareti Kọ̀ Jesu fún Ìgbà Àkọ́kọ́
- Jesu Fi Kapernaumu Ṣe Ilé Rẹ̀
- Nínú Àwọn Apẹja Mẹ́rin Jesu Rí Àwọn Apẹja Ènìyàn
- Jesu Wo Ọkùnrin Tí Ẹ̀mí Èṣù Ní Sàn nínú Sinagọgu
- Jesu Wo Ìyá Ìyàwó Peteru àti Ọ̀pọ̀ Àwọn Mìíràn Sàn
- Ìrìn Àjò Àkọ́kọ́ Káàkiri Galili àti Ìpè Matiu
- Jesu Rìnrìn Àjò Káàkiri Galili fún Ìgbà Àkọ́kọ́ pẹ̀lú Àwọn Apẹja Mẹ́rin
- Jesu Wo Adẹ́tẹ̀ Kan Sàn
- Jesu Wo Ẹlẹ́gbàá Tí A Sọ̀ Kalẹ̀ Nípasẹ̀ Òrùlé Sàn
- Jesu Pe Matiu, Ẹni Tí Ó Ṣe Àsè Ìtẹ́wọ́gbà fún Un
- Jesu Gbèjà Àwọn Ọmọ-ẹ̀yìn Rẹ̀ fún Àìgbààwẹ̀
- Àríyànjiyàn náà nípa ọjọ́ ìsinmi ní Jerusalẹmu àti Galili
- Jesu Wo Arọ Kan Sàn ní ọjọ́ ìsinmi
- Àwọn Ọmọ-ẹ̀yìn Já Ọkà ní ọjọ́ ìsinmi
- Jesu Wo Ọwọ́ Gbígbẹ Kan Sàn ní ọjọ́ ìsinmi
- Jesu Yan Àwọn Méjìlá Ó sì Wàásù Lórí Òkè
- Jesu Kọ́ Àwọn Ogunlọ́gọ̀ Púpọ̀ Ó sì Wò Wọ́n Sàn Lẹ́gbẹ̀ẹ́ Òkun
- Jesu Yan Àpọ́sítélì Méjìlá
- Ìwàásù Lórí Òkè
- Ìpa Kristi Ń Pọ̀ Sí I, Johanu Sì Béèrè Láti Ẹ̀wọ̀n
- Jesu Wo Ìránṣẹ́ Ọ̀gágun Ọgọ́rùn-ún Sàn ní Kapernaumu
- Jesu Jí Ọmọ Opó Kan Dìde ní Naini
- Johanu Ránṣẹ́, Jesu Sì Yìn Ín
- Ègbé fún àwọn ìlú tí a fún ní àǹfààní
- Obìnrin Ẹlẹ́ṣẹ̀ Kan Fi Òróró Kùn Ẹsẹ̀ Kristi
- Ìrìn Àjò Kejì Ká Galili àti Ìṣọ̀tá Àwọn Farisi
- Jesu Rìn Ká Galili fún Ìgbà Kejì
- A Fi Ẹ̀sùn Kan Jesu Pé Ó Bá Beelsebulu Ṣọ̀rẹ́ Pọ̀
- Àwọn akọ̀wé àti Farisi fi ìtẹnumọ́ béèrè àmì
- Ìyá àti Àwọn Arákùnrin Kristi Wá Ọ̀nà Láti Mú Un Lọ Sí Ilé
- Àwọn Òwe, Gerasa, àti Ìbẹ̀wò Ìkẹyìn sí Nasareti
- Àkójọpọ̀ Ńlá Àkọ́kọ́ ti Àwọn Òwe
- Jesu Mú Ìjì Dákẹ́ Nígbà Tí Ó Ń La Adágún Kọjá
- Jesu Wo Ará Gerasa Tí Ẹ̀mí Èṣù Ní Lára Dá
- Ọmọbìnrin Jairu àti Obìnrin Tí Ó Fọwọ́ Kan Aṣọ Kristi
- Jesu Wo Àwọn Afọ́jú Méjì àti Ọkùnrin Odi Kan Dá
- Jesu Ṣèbẹ̀wò Sí Nasareti Fún Ìgbà Ìkẹyìn
- Ìrìnàjò Kẹta Káàkiri Galili àti Ipa Rẹ̀ Lórí Herodu
- Jesu Rìnrìn Àjò Káàkiri Galili Fún Ìgbà Kẹta
- Ìbẹ̀rù Herodu Nípa Jesu Nítorí Ẹ̀bi Ọkàn Rẹ̀
-
29 tàbí 28 lẹ́yìn ìbí KristiApá 8: Jesu Kọ́ Àwọn Méjìlá Ní Àyíká Galili 29 tàbí 28 lẹ́yìn ìbí Kristi
- Jesu Bọ́ Ẹgbẹ̀rún Márùn-ún Ènìyàn
- A Dá Ètò Láti Fi Jesu Jọba Dúró
- Kristi Wá Bá Àwọn Méjìlá Lórí Omi
- A Kí Jesu Káàbọ̀ Ní Genesareti
- Ìpolongo Láàárín Àwọn Ará Galili Wó Lulẹ̀
- Àwọn Farisi Bá Jesu Wí Nítorí Ọwọ́ Àìwẹ̀
- Jesu Wo Ọmọbìnrin Obìnrin Ará Siro-Fonisia Kan Dá
- Jesu Bọ́ Ẹgbẹ̀rún Mẹ́rin Ènìyàn
- Àwọn Farisi àti Sadusi Kọlu Jesu Ní Magadani
- Jesu Wo Ọkùnrin Afọ́jú Kan Dá Ní Betisaida
- Jesu Dán Ìgbàgbọ́ Àwọn Méjìlá Wò
- Jesu Sọ Tẹ́lẹ̀ Nípa Ikú àti Àjíǹde Rẹ̀
- Wíwá Ọmọ Ènìyàn Ní Ìran Náà
- Ìrísí Jesu Yí Padà Lórí Òkè Kan
- Àwọn Ọmọ-ẹ̀yìn Mẹ́ta Dààmú Nípa Elijah
- Ọmọkùnrin Tí Ẹ̀mí Èṣù Ní Tí Àwọn Ọmọ-ẹ̀yìn Kò Lè Wò Sàn
- Jesu Tún Sọ Àsọtẹ́lẹ̀ Ikú àti Àjíǹde Rẹ̀
- Jesu San Owó Orí Tẹmpili Ti Ìdajì Ṣékélì
- Àwọn Méjìlá Jiyàn Nípa Ẹni Tó Tóbi Jù Lọ
- Jesu Bá Johanu Wí Nítorí Ìtara Rẹ̀ Tí Kò Tọ́
- Bí A Ṣe Lè Hùwà Sí Arákùnrin Tó Dẹ́ṣẹ̀ Kí A Sì Dárí Jì Í
- Àwọn Ọmọlẹ́yìn Messia Gbọdọ̀ Fi Ohun Gbogbo Sílẹ̀
- Jesu Kọ Ìmọ̀ràn Àwọn Arákùnrin Rẹ̀
- Jesu Lọ Sí Jerusalẹmu Ní Ìkọ̀kọ̀ Nípa Gbigba Samaria Kọjá
-
29 tàbí 28 lẹ́yìn ìbí KristiApá 9: Iṣẹ́ Ìránṣẹ́ Ní Judea Ní Àkókò Tó Tẹ̀ Lé 29 tàbí 28 lẹ́yìn ìbí Kristi
- Jesu Mú Kí Ìtara Ru Sókè Ní Àjọ̀dún àgọ́
- Ìtàn Obìnrin Panṣágà Tí A Mú Wá Sí Ọ̀dọ̀ Jesu
- Jesu Sọ Pé Òun Ni Ìmọ́lẹ̀ Ayé
- Àwọn Farisi Gbìyànjú Láti Sọ Jesu Ní Òkúta
- Jesu Wo Ọkùnrin Tí A Bí Ní Afọ́jú Sàn
- Òwe Olùṣọ́ Àgùntàn Rere
- Rírán Àwọn Àádọ́rin Lọ
- Òwe Ará Samaria Rere
- Jesu Jẹ́ Àlejò Marta àti Maria
- Jesu Tún Fúnni Ní Àpẹẹrẹ Àdúrà
- Ẹ̀sùn Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ Pẹ̀lú Beelsebulu Tí Ó Jẹ́ Ọ̀rọ̀ Òdì
- Jesu Dá Àwọn Farisi àti Àwọn Amòfin Lẹ́bi
- Jesu Kìlọ̀ nípa Àgàbàgebè, Ojúkòkòrò àti Àníyàn
- Gbogbo Ènìyàn Gbọdọ̀ Ronúpìwàdà tàbí Kí Wọ́n Ṣègbé
- Jesu Wo Obìnrin Arọ Kan Sàn ní ọjọ́ ìsinmi
- Ní Àjọ̀dún Ìyàsímímọ́, Àwọn Júù Gbìyànjú láti sọ Jesu lókùúta
-
29 sí 30 lẹ́yìn ìbí KristiApá 10: Iṣẹ́ Ìránṣẹ́ ní Perea ní Àkókò Ìkẹyìn 29 sí 30 lẹ́yìn ìbí Kristi
- Jesu Fàsẹ́yìn Lọ sí Betani ní Òdìkejì Jordani
- Jesu Kọ́ni ní Perea, A sì Kìlọ̀ fún Un nípa Herodu
- Nígbà tí Jesu Ń Jẹun pẹ̀lú Olórí Farisi Kan, Ó Tún Wo Aláìsàn Sàn
- Jesu Kìlọ̀ fún Àwọn Ogunlọ́gọ̀ láti Ṣírò Ohun tí Yóò Ná Wọn
- Àgùntàn Tí Ó Sọnù, Owó Ẹyọ Tí Ó Sọnù àti Ọmọ Tí Ó Sọnù
- Òwe Mẹ́ta nípa Iṣẹ́ Ìríjú
- Jesu Jí Lasaru Dìde kúrò nínú Òkú
- Àwọn Àbájáde Jíjí Lasaru Dìde
- Jesu Bẹ̀rẹ̀ Ìrìnàjò Rẹ̀ Ìkẹyìn sí Jerusalẹmu
- Òwe Méjì nípa Àdúrà
- Jesu Kọ́ni nípa Ìkọ̀sílẹ̀
- Kristi àti Àwọn Ọmọdé
- Ọ̀dọ́ Aláṣẹ Ọlọ́rọ̀ àti Àwọn Ewu Ọrọ̀
- Jesu Sọ Nípa Ikú Rẹ̀ Ṣáájú, Ó sì Bá Jakọbu àti Johanu Wí
- Jesu Wo Bartimeu Afọ́jú àti Ẹlẹgbẹ́ Rẹ̀ Sàn
- Jesu Ṣèbẹ̀wò sí Sakeu
-
30 tàbí 29 lẹ́yìn ìbí KristiApá 11: Iṣẹ́ Ìránṣẹ́ Ìkẹyìn ní Gbangba ní Jerusalẹmu 30 tàbí 29 lẹ́yìn ìbí Kristi
- Jesu Dé Betani nítòsí Jerusalẹmu
- Jesu Wọ Jerusalẹmu pẹ̀lú Ìṣẹ́gun gẹ́gẹ́ bí Messia
- A Gégùn-ún fún Igi Ọ̀pọ̀tọ́, A sì Tún Wẹ Tẹ́ńpìlì Mọ́
- Àwọn Helleni Kan Fẹ́ Rí Jesu
- A Rí Igi Ọ̀pọ̀tọ́ Tí Kò So Èso Pé Ó Ti Rọ
- Ìgbìmọ̀ àwọn àgbà Júù Pe Àṣẹ Jesu Níjà
- Àwọn Farisi àti àwọn ọmọ-ẹ̀yìn Herodu Gbìyànjú láti Dẹ Jesu Mú lórí Ọ̀ràn Owó Orí
- Ìbéèrè Àdììtú àwọn Sadusi nípa Àjíǹde
- Farisi Kan Tí Ó Jẹ́ Amòfin Bi Jesu Léèrè
- Jesu Pa Àwọn Ọ̀tá Rẹ̀ Lẹ́nu Mọ́ lórí Ọ̀ràn Ọmọ Dafidi
- Jesu Dá Àwọn Akọ̀wé àti àwọn Farisi Lẹ́bi
- Jesu Yin Ẹ̀bùn Opó Tálákà Náà
-
30 tàbí 29 lẹ́yìn ìbí KristiApá 12: Nínú Òjìji pẹ̀lú Jesu 30 tàbí 29 lẹ́yìn ìbí Kristi
- Ọ̀rọ̀ Pàtàkì nípa Àwọn Àkókò Ìkẹyìn
- Jesu Sọ Tẹ́lẹ̀ Pé A Ó Kàn Òun Mọ́ Àgbélébùú ní Ọjọ́ Méjì
- Maria ti Betani Fi Òróró Yan Jesu fún Ìsìnkú
- Judasi Dúnàádúrà láti Fi Jesu Hàn
- Ṣíṣe Oúnjẹ Ìrékọjá Sílẹ̀ ní Ilé Ọ̀rẹ́ Kan
- Jesu Jẹ Oúnjẹ Ìrékọjá Pẹ̀lú Àwọn Méjìlá
- Jesu Wẹ Ẹsẹ̀ Àwọn Ọmọ-ẹ̀yìn Rẹ̀
- Jesu Tọ́ka sí Judasi Gẹ́gẹ́ Bí Ọ̀dàlẹ̀
- Jesu Kìlọ̀ fún Àwọn Ọmọ-ẹ̀yìn pé Kí Wọ́n Má Ṣe Kọ Òun Sílẹ̀
- Jesu Dá Ayẹyẹ Ìrántí Àkàrà àti Wáìnì Sílẹ̀
- Ọ̀rọ̀ Ìdágbére nínú Yàrá Òkè
- Ọ̀rọ̀ Ẹ̀kọ́ ní Ọ̀nà sí Getsemane
- Àdúrà Ìbẹ̀bẹ̀ Kristi fún Àwọn Ẹlòmíràn
- Jesu Wà nínú Ìrora Líle fún Ìgbà Pípẹ́ ní Getsemane
-
30 tàbí 29 lẹ́yìn ìbí KristiApá 13: Ìmú, Ìgbẹ́jọ́, Ìkànmọ́ Àgbélébùú, àti Ìsìnkú Jesu 30 tàbí 29 lẹ́yìn ìbí Kristi
- A Da Jesu Lẹ́, A Mú Un, A sì Kọ̀ Ọ́ Sílẹ̀
- Annasi Kọ́kọ́ Wádìí Jesu Lẹ́nu Wò
- Kaiafa àti ìgbìmọ̀ àwọn àgbà Júù Dá Jesu Lẹ́bi
- Peteru Sẹ́ Olúwa Rẹ̀ Nígbà Mẹ́ta
- Ìgbìmọ̀ ilé ẹjọ́ tí ó ga jùlọ dá Jesu lẹ́bi ní ìbámu pẹ̀lú ìlànà lẹ́yìn tí ilẹ̀ mọ́
- Ìkábàámọ̀ àti Ìpara-ẹni Judasi Ọ̀dàlẹ̀
- Jesu níwájú Pilatu fún Ìgbà Àkọ́kọ́
- Jesu níwájú Herodu Antipa Alákòóso Ìdámẹ́rin Ìjọba
- Jesu níwájú Pilatu fún Ìgbà Kejì
- Àwọn Ọmọ Ogun ará Romu Fi Jesu Ṣe Ẹlẹ́yà
- Jesu ní Ọ̀nà sí Agbélébùú
- Wákàtí Mẹ́ta Àkọ́kọ́ lórí Agbélébùú
- Wákàtí Mẹ́ta Òkùnkùn
- Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Tí Ó Bá Ikú Kristi Lọ
- A Sin Jesu sínú Ibojì Josẹfu ti Arimatea
- Àwọn Obìnrin Ṣọ́ Ibojì Jesu
-
30 tàbí 29 lẹ́yìn ìbí KristiApá 14: Àjíǹde àti Ìgòkè Ọ̀run Kristi 30 tàbí 29 lẹ́yìn ìbí Kristi
- Àwọn Obìnrin Ṣèbẹ̀wò sí Ibojì Jesu
- Áńgẹ́lì Kan Yí Òkúta Kúrò
- Àwọn Áńgẹ́lì Sọ fún Àwọn Obìnrin nípa Ibojì Òfìfo
- Peteru àti Johanu Ṣèbẹ̀wò sí Ibojì Òfìfo
- Jesu Farahàn Maria Magdalene
- Jesu Farahàn Àwọn Obìnrin Yòókù
- Àwọn Kan lára Àwọn Ẹ̀ṣọ́ Sọ Ìròyìn fún Àwọn Alákòóso Júù
- Jesu Farahàn Àwọn Ọmọ-ẹ̀yìn Méjì ní Ọ̀nà sí Emmausi
- Àwọn Ọmọ-ẹ̀yìn Méjì Padà Sọ Ìròyìn
- Jesu Farahàn Àwọn Ọmọ-ẹ̀yìn Láìsí Tomasi
- Jesu Tún Farahàn, Tomasi sì Gbàgbọ́
- Jesu Farahàn Àwọn Ọmọ-ẹ̀yìn Méje lẹ́gbẹ̀ẹ́ Òkun Galili
- Jesu Farahàn Àwọn Tí Ó Lé ní Ẹ̀ẹ́dẹ́gbẹ̀ta ní Galili
- Jesu Fún Àwọn Ọmọ-ẹ̀yìn ní Iṣẹ́ Mìíràn
- Ìfarahàn Ìkẹyìn àti Ìgòkè Ọ̀run
-
29 sí 96 lẹ́yìn ìbí Kristi
Láti Ìṣe àwọn Aposteli sí Ìfihàn
29 sí 96 lẹ́yìn ìbí Kristi-
29 sí 40 lẹ́yìn ìbí KristiApá 1: Ìwàásù Ìhìnrere fún Àwọn Júù Nìkan 29 sí 40 lẹ́yìn ìbí Kristi
- Àwọn Aposteli Padà sí Jerusalẹmu
- A Yan Mattia Nípa Kèké láti Rọ́pò Judasi
- Ẹ̀mí Mímọ́ Dé ní Pentikosti
- Peteru Bá Ọ̀pọ̀ Ènìyàn Sọ̀rọ̀
- Àwọn Àbájáde Ọ̀rọ̀ Peteru
- Ìṣọ̀kan Àwọn Olùyípadà Àkọ́kọ́
- 30 lẹ́yìn ìbí KristiPeteru àti Johanu Wo Ọkùnrin Arọ Kan Sàn 30 lẹ́yìn ìbí Kristi
- Peteru Tún Bá Àwọn Ènìyàn Sọ̀rọ̀
- Ìgbìmọ̀ Fi Peteru àti Johanu Sẹ́wọ̀n
- Peteru Bá Ìgbìmọ̀ Sọ̀rọ̀
- Ìjọ Gbadura Nígbà tí A Tú Peteru àti Johanu Sílẹ̀
- Ìṣọ̀kan àti Ọ̀làwọ́ Ìjọ Àkọ́kọ́bẹ̀rẹ̀
- Ikú Anania àti Safira
- 31 lẹ́yìn ìbí KristiIpò Ìjọ ní Àkókò Yìí 31 lẹ́yìn ìbí Kristi
- 32 lẹ́yìn ìbí KristiÁńgẹ́lì Kan Tú Àwọn Aposteli Kúrò nínú Ẹ̀wọ̀n 32 lẹ́yìn ìbí Kristi
- Peteru Sọ fún Ìgbìmọ̀ pé Kristi Ni Messia
- Ìmọ̀ràn Gamalieli Mú kí A Tú Àwọn Aposteli Sílẹ̀
- Yíyan Àwọn Diakoni Méje
- 33 lẹ́yìn ìbí KristiIye Àwọn Ènìyàn Nínú Ìjọ Ń Pọ̀ Sí I 33 lẹ́yìn ìbí Kristi
- 33 tàbí 34 lẹ́yìn ìbí KristiA Fi Ẹ̀sùn Ọ̀rọ̀ Òdì Kàn Stefanu 33 tàbí 34 lẹ́yìn ìbí Kristi
- Ìgbèjà Stefanu níwájú Ìgbìmọ̀
- Stefanu Bá Ìgbìmọ̀ Wí
- 34 lẹ́yìn ìbí KristiA Sọ Stefanu ní Òkúta Pa 34 lẹ́yìn ìbí Kristi
- Inúnibíni Gbogbogbò sí Àwọn Kristiani
- Filipi Wàásù ní Samaria
- Peteru àti Johanu Sọ̀kalẹ̀ Wá sí Samaria
- Peteru Bá Simoni Onídán Wí
- Peteru àti Johanu Wàásù ní Ọ̀pọ̀ Abúlé Àwọn Ará Samaria
- Filipi Ṣe Ìrìbọmi fún Akápò Ayaba Kandake
- Àwọn Olùyípadà tí Ó Fọ́nká Wàásù fún Àwọn Júù
- 35 lẹ́yìn ìbí KristiSaulu Yí Padà ní Ọ̀nà sí Damasku 35 lẹ́yìn ìbí Kristi
- A Batisí Saulu
- 38 lẹ́yìn ìbí KristiSaulu Wàásù fún Àwọn Júù nínú Àwọn Sinagọgu 38 lẹ́yìn ìbí Kristi
- 38 sí 40 lẹ́yìn ìbí KristiPeteru Wo Aenea Sàn, Ó sì Jí Dọkasi Dìde 38 sí 40 lẹ́yìn ìbí Kristi
- 40 lẹ́yìn ìbí KristiÀwọn Ìjọ Ní Ìsinmi Kúrò nínú Inúnibíni 40 lẹ́yìn ìbí Kristi
-
40 sí 45 lẹ́yìn ìbí KristiApá 2: A Wàásù Ìhìnrere fún Àwọn Aláìkọlà Olùfọkànsìn 40 sí 45 lẹ́yìn ìbí Kristi
- Ìran Kan Rán Peteru sí Aláìkọlà Kan
- Peteru Bẹ Korneliu Wò, Ọ̀gágun Ọgọ́rùn-ún Ọmọ Ogun tí Ó Jẹ́ Ará Romu
- Peteru Kéde Kristi Gẹ́gẹ́ bí Olùgbàlà Gbogbo Ènìyàn
- Korneliu àti Àwọn Ọ̀rẹ́ Rẹ̀ Gba Ẹ̀mí
- Peteru Gbéjà Bíbatisí Korneliu
- 41 lẹ́yìn ìbí KristiÀwọn Ẹni Tí Ó Yí Padà Tí Wọ́n Fọ́nká Wàásù fún Àwọn Aláìkọlà Olùfọkànsìn 41 lẹ́yìn ìbí Kristi
- Ìjọ Jerusalẹmu Rán Barnaba
- 42 lẹ́yìn ìbí KristiBarnaba Mú Saulu Láti Tarsu Wá sí Antioku 42 lẹ́yìn ìbí Kristi
- 43 lẹ́yìn ìbí KristiHerodu Dá Jakọbu Lẹ́bi, Ó sì Fi Peteru Sẹ́wọ̀n 43 lẹ́yìn ìbí Kristi
- ní nǹkan bí 44 lẹ́yìn ìbí KristiAntioku Fi Ìrànlọ́wọ́ Ránṣẹ́ sí Jerusalẹmu ní nǹkan bí 44 lẹ́yìn ìbí Kristi
- 44 lẹ́yìn ìbí KristiIkú Herodu Agrippa 44 lẹ́yìn ìbí Kristi
- Àwọn Ìjọ Ń Bá a Lọ láti Máa Dàgbà
- 45 lẹ́yìn ìbí KristiSaulu Padà Pẹ̀lú Barnaba sí Antioku 45 lẹ́yìn ìbí Kristi
-
45 sí 49 lẹ́yìn ìbí KristiApá 3: A Wàásù Ìhìnrere fún Àwọn Aláìkọlà Abọ̀rìṣà 45 sí 49 lẹ́yìn ìbí Kristi
- Antioku Ya Saulu àti Barnaba Sọ́tọ̀
- Saulu Bẹ̀rẹ̀ Ìrìnàjò Míṣọ́nnárì Àkọ́kọ́ Rẹ̀
- Segiu Paulusi Yí Padà ní Saipurọsi
- Láti Saipurọsi sí Perga ní Pamfilia
- 46 lẹ́yìn ìbí KristiPaulu Wàásù fún Àwọn Júù ní Antioku ti Pisidia 46 lẹ́yìn ìbí Kristi
- Àwọn Ènìyàn ní Ikoniomu Ń Múra láti Sọ Wọ́n Lókùúta
- Lysra Gbìyànjú láti Rú Ẹbọ sí Wọn, Lẹ́yìn Náà Ó Sọ Wọ́n Lókùúta
- 47 lẹ́yìn ìbí KristiLáti Lysra sí Dabe 47 lẹ́yìn ìbí Kristi
- Paulu àti Barnaba Tún Bẹ Àwọn Ìjọ Wò
- 48 lẹ́yìn ìbí KristiNípasẹ̀ Pisidia sí Perga àti Atalia 48 lẹ́yìn ìbí Kristi
- Wọ́n Ròyìn fún Ìjọ ní Antioku
- Àríyànjiyàn ní Antioku lórí Ìkọlà
- 49 lẹ́yìn ìbí KristiÌpinnu Jakọbu àti Ìjọ Jerusalẹmu 49 lẹ́yìn ìbí Kristi
- Paulu àti Barnaba Mú Ìpinnu náà Wá sí Antioku
-
50 sí 54 lẹ́yìn ìbí KristiApá 4: Ìrìnàjò Míṣọ́nnárì Kejì ti Paulu 50 sí 54 lẹ́yìn ìbí Kristi
- Paulu Dábàá Ṣíṣàbẹ̀wò sí Àwọn Ìjọ Lẹ́ẹ̀kan Sí I
- Paulu Yapa kúrò lọ́dọ̀ Barnaba
- Paulu Mú Timotiu Lọ Pẹ̀lú Rẹ̀
- Láti Ikoniomu sí Frigia àti Galatia
- Láti Galatia sí Misia àti Troasi
- Láti Troasi sí Samotrakea
- A Dá Afọ̀ṣẹ̀ Sílẹ̀, Ẹ̀ṣọ́ Ẹ̀wọ̀n sì Yí Padà
- Láti Filipi sí Tẹsalonika
- 51 lẹ́yìn ìbí KristiPaulu Kọ̀wé sí Àwọn ará Galatia 51 lẹ́yìn ìbí Kristi
- Àwọn ará Galatia Kọ Ìgbàgbọ́ Wọn Àkọ́kọ́ Sílẹ̀
- Òfin Kéré sí Májẹ̀mú Ìhìnrere
- Àwọn Júù Berea Múra Tán láti Gba Ìhìnrere
- Paulu Wàásù fún Àwọn Onímọ̀ Ọgbọ́n ní Ateni
- Paulu Ṣiṣẹ́ láti Gbọ́ Bùkátà Ara Rẹ̀ ní Kọrinti
- Paulu Kọ̀wé sí Àwọn Ará Tẹsalonika
- Ìpè sí Ìwà Mímọ́ àti Ìwà Fúnfun
- Paulu Dúró ní Kọrinti, Ó Ń Wàásù fún àwọn aláìkọlà
- 52 lẹ́yìn ìbí KristiPaulu Tún Kọ̀wé sí Àwọn Ará Tẹsalonika 52 lẹ́yìn ìbí Kristi
- A Mú Paulu Wá síwájú Gallioni
- 53 lẹ́yìn ìbí KristiPaulu Kọ̀wé sí Titu 53 lẹ́yìn ìbí Kristi
- 54 lẹ́yìn ìbí KristiLáti Kenkerea sí Efesu 54 lẹ́yìn ìbí Kristi
- Paulu Parí Ìrìn Àjò Rẹ̀ Kejì ní Antioku
-
55 sí 60 lẹ́yìn ìbí KristiApá 5: Ìrìn Àjò Ìjíhìnrere Kẹta Paulu 55 sí 60 lẹ́yìn ìbí Kristi
- Paulu Tún Ṣèbẹ̀wò sí Galatia àti Frigia
- Apollo Wàásù ní Efesu
- Láti Frigia sí Efesu
- 56 lẹ́yìn ìbí KristiA Jó Àwọn Ìwé Idán ní Efesu 56 lẹ́yìn ìbí Kristi
- Paulu Rán Timotiu àti Erastu sí Makedonia àti Akaia
- 57 lẹ́yìn ìbí KristiPaulu Kọ̀wé sí Àwọn ará Kọrinti 57 lẹ́yìn ìbí Kristi
- Ìpínyà Nítorí Àwọn Òjíṣẹ́ Ń Pa Ìgbésí Ayé Ẹ̀mí Run
- Lé Ọkùnrin Tí Ó Bá Ìbátan Rẹ̀ Lòpọ̀ Jáde
- Ẹ̀sìn Kristiani Kò Yí Ìbáṣepọ̀ Ìgbésí Ayé Padà
- Paulu Gbé Ẹ̀tọ́ Rẹ̀ Gẹ́gẹ́ Bí Aposteli Lẹ́yìn
- Àwọn Oúnjẹ Tí Òfin Yọ̀ǹda àti Àǹfààní Àwọn Ẹlòmíràn
- Ẹ̀mí Kan, Ọ̀pọ̀ Ẹ̀bùn Ẹ̀mí
- Sísọtẹ́lẹ̀ Sàn Ju Sísọ Èdè Lọ
- Àwọn Ẹlẹ́rìí Àjíǹde Kristi
- Adamu Àkọ́kọ́ àti Èkejì
- Demetriusi Ru Ọ̀pọ̀ Ènìyàn Sókè sí Ìdàrúdàpọ̀ ní Efesu
- Paulu Kúrò ní Efesu Lọ sí Makedonia
- Paulu Kọ̀wé sí Timotiu
- Paulu Fún Àwọn Ọkùnrin àti Obìnrin ní Ìtọ́ni nípa Ìjọsìn
- Ìwà Timotiu Sí Àwọn Àgbà àti Àwọn Opó
- Paulu Tẹ̀ Síwájú Sí Giriki
- 58 lẹ́yìn ìbí KristiPaulu Tún Kọ̀wé Sí Àwọn ará Kọrinti 58 lẹ́yìn ìbí Kristi
- Àwọn ará Kọrinti Ni Lẹ́tà Paulu
- Ìdí Tí Paulu Fi Ń Wàásù Pẹ̀lú Ìtara Tó Bẹ́ẹ̀
- Paulu Rọni Láti Fún Judea Ní Ọ̀pọ̀lọpọ̀
- Paulu Bá Dídájọ́ Nípa Ìrísí Òde Wí
- Àwọn Ìran àti Ìfihàn Paulu
- Paulu Padà Láti Kọrinti sí Makedonia
- Paulu Kọ̀wé sí Àwọn Ará Romu
- Mímọ Òfin Kò Lè Dá Júù Láre
- A Dá Abrahamu Láre Kí Ó Tó Kọlà
- Ìtẹ̀bọmi Dì Kristiani Mọ́ Ìwà Mímọ́
- Kò Sí Ìdálẹ́bi Fún Àwọn Tí Ó Wà Nínú Kristi
- Ọlọ́run Fi Òmìnira Yàn Jakọbu Dípò Esau
- Àwọn Àyànfẹ́ Rí I Gbà, A Fọ́ Àwọn Yòókù Lójú
- Ẹ Ṣègbọràn sí Àwọn Aláṣẹ, Ẹ San Owó Orí, Kí Ìfẹ́ Nìkan Ni Gbèsè Yín
- Iṣẹ́ ìránṣẹ́ Paulu sí àwọn aláìkọlà àti àwọn ètò rẹ̀
- Paulu jí Eutiku dìde ní Troasi
- Láti Troasi sí Asosi àti Miletu
- Láti Miletu sí Kiosi
- Ìdágbére Paulu fún àwọn àgbà ará Efesu
- Paulu fi ọkọ̀ ojú omi lọ láti Miletu sí Tire
- Paulu àti Luku dúró fún ọjọ́ méje ní Tire
- Láti Tire sí Pitolemai
- Agabu sọ tẹ́lẹ̀ nípa fífi Paulu sẹ́wọ̀n
- Paulu àti Luku dé Jerusalẹmu
- Ọ̀pọ̀ ènìyàn onírúkèrúdò tí àwọn Júù láti Asia rú sókè yọrí sí mímú Paulu
- Paulu gbèjà ara rẹ̀ níwájú ogunlọ́gọ̀
- Àwọn Júù béèrè pé kí a pa Paulu
- Paulu béèrè ẹ̀tọ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọmọ ìlú ará Romu
- Paulu Níwájú Ìgbìmọ̀
- Ìran kan gba Paulu níyànjú láti fara dà á
- A mú Paulu lọ sí Kesarea ní òru
- A fi ẹ̀sùn ìṣọ̀tẹ̀ kan Paulu níwájú Feliksi
- A pa Paulu mọ́ sínú ẹ̀wọ̀n títí Festu fi dé
- 60 lẹ́yìn ìbí KristiPaulu fi ọ̀ràn rẹ̀ lọ Augustu 60 lẹ́yìn ìbí Kristi
- Festu sọ fún Agrippa nípa àwọn ẹ̀sùn tí a fi kan Paulu
- Paulu gbèjà ara rẹ̀ níwájú Festu àti Agrippa
- A fi Paulu lé ọ̀gágun ọgọ́rùn-ún lọ́wọ́
-
60 sí 62 lẹ́yìn ìbí KristiApá 6: Ìrìn àjò kẹrin Paulu 60 sí 62 lẹ́yìn ìbí Kristi
- Paulu bẹ̀rẹ̀ ìrìn àjò ojú omi sí Romu gẹ́gẹ́ bí ẹlẹ́wọ̀n
- Ọkọ̀ ojú omi dúró ní Sidoni ó sì lọ sí Saipurọsi
- Wọ́n pààrọ̀ ọkọ̀ ojú omi wọ́n sì tẹ̀síwájú sí Krete
- Paulu Kìlọ̀ fún Ọ̀gá Ọkọ̀ Ojú Omi Nípa Ewu
- Ìfọ́ Ọkọ̀ Ojú Omi: Gbogbo Àwọn Tó Wà Nínú Rẹ̀ Là
- Wọ́n Gúnlẹ̀ sí Erékùṣù Mẹlita
- Lẹ́yìn Oṣù Mẹ́ta Wọ́n Fi Ọkọ̀ Ojú Omi Lọ sí Romu
- Àwọn Arákùnrin Kí Paulu Káàbọ̀ ní Romu
- Paulu Pe Àwọn Júù ní Romu Jọ
- 61 lẹ́yìn ìbí KristiPaulu Kọ̀wé sí Àwọn ará Efesu 61 lẹ́yìn ìbí Kristi
- A Ṣí Àṣírí Àwọn aláìkọlà Payá fún Paulu
- Ẹ Fara Wé Ọlọ́run, Kí Ẹ sì Máa Gbé Bí Ọmọ Ìmọ́lẹ̀
- 62 lẹ́yìn ìbí KristiPaulu Kọ̀wé sí Àwọn Ará Filipi 62 lẹ́yìn ìbí Kristi
- Timotiu Yóò Wá, A Rán Epafiroditu Ní Báyìí
- Paulu Kọ̀wé sí Àwọn ará Kolose
- Èé Ṣe Tí Ẹ Fi Ń Pa Òfin Ènìyàn Mọ́ Lẹ́yìn Tí Ẹ Ti Kú Pẹ̀lú Kristi?
- Paulu Kọ̀wé sí Filemoni
- Jakọbu Kọ̀wé sí àwọn Kristiani Júù
- Ahọ́n Tí Kò Sí Ẹni Tí Ó Lè Tẹ̀ Lójú
- Paulu Lo Ọdún Méjì ní Romu
-
62 sí 96 lẹ́yìn ìbí KristiApá 7: Ìrìnàjò Ìkẹyìn Paulu àti Ìparí Àkójọpọ̀ Àwọn Ìwé Mímọ́ 62 sí 96 lẹ́yìn ìbí Kristi
- Paulu Kọ̀wé sí Àwọn Heberu
- Ìsinmi Ọjọ́ Ìsinmi Kan Ṣì Kù fún Àwọn Onígbàgbọ́
- Melkisedeki, Àpẹẹrẹ Kristi
- Kristi Wọ Ọ̀run Pẹ̀lú Ẹ̀jẹ̀ Tirẹ̀ Fúnra Rẹ̀
- Ẹ Rántí Àwọn Ọjọ́ Àtijọ́ Kí Ẹ Sì Fara Dà Á
- Ìbáwí Jẹ́ Àmì Ìfẹ́ Ọlọ́run
- 65 lẹ́yìn ìbí KristiPaulu Tún Kọ̀wé sí Timotiu 65 lẹ́yìn ìbí Kristi
- 65 tàbí 66 lẹ́yìn ìbí KristiPaulu Ránni Létí Ìyapa Kúrò Nínú Ìgbàgbọ́ Tí A Ti Sọtẹ́lẹ̀ 65 tàbí 66 lẹ́yìn ìbí Kristi
- Peteru kọ̀wé sí àwọn Kristiani Júù àti aláìkọlà
- Àwọn Ojúṣe Aya àti Ọkọ Kristiani
- 66 lẹ́yìn ìbí KristiPeteru tún kọ̀wé sí àwọn Kristiani Júù àti aláìkọlà 66 lẹ́yìn ìbí Kristi
- Juda Kọ̀wé sí Ìjọ
- 96 lẹ́yìn ìbí KristiJohanu Kọ Ìfihàn 96 lẹ́yìn ìbí Kristi
- Sí Sardi àti Àwọn Ìjọ Tí Ìtara Wọn Ń Dín Kù
- Èdìdì Kìíní: Ìhìnrere Ṣẹ́gun
- Ìpè Karùn-ún: Mùhámádù àti Àwọn Saracen
- Ìpè Keje: Ìjọ Yọ̀
- Áńgẹ́lì Mẹ́ta Rọ Aráyé
- Àwokòtò Keje: Ogun Amagedoni
- Ìjọ Yọ̀ lórí Ìṣubú Àwọn Ọ̀tá Rẹ̀
- Jerusalẹmu Tuntun àti Paradise Tuntun Kan
- Johanu Kọ̀wé láti Tako Àwọn Olùkọ́ Èké
- Ìfẹ́ Tí A Fi Iṣẹ́ Hàn, Kì Í Ṣe Ọ̀rọ̀
- Lẹ́tà Kejì ti Johanu
- Johanu Kọ̀wé sí Ìyá Kan àti Àwọn Ọmọ Rẹ̀
- Lẹ́tà Kẹta ti Johanu
- Johanu Kọ̀wé sí Gaiusi
-